YO/Prabhupada 0658 - Srimad-Bhagavatam Is The Supreme Jnana-yoga and Bhakti-yoga Combined



Lecture on BG 6.13-15 -- Los Angeles, February 16, 1969

Olufokansi: Gbogbo ogo si Srila Prabhupada.

Prabhupāda: Hare Kṛṣṇa. Sāṅkhya-yoga ni aṣṭāṅga-yoga. Ijoko ati lati sasaro, nkan tonpe ni sankhya-yoga niyen. Lati imo ikeeko nitumo jnana-yoga. Pelu imo nkan tio kinse Brahman ati nkan toje Brahman. Neti neti. Jnan-yoga niyen. Gege bi Vedānta-sūtra, jñāna-yoga. Teyin ba ka Vedānta-sūtra, o sowipe janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Wanti juwe funwa pe Brahman to gaju yi, lati Otito to gaju yi ni gbogbo awon nkan ti wa. Nisin awa tin gbiyanju lati mo nkan toje. Wanti salaaye ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Iwa otito to gaju yi. Otito to gaju yi, ninu ese iwe kini Śrīmad-Bhāgavatam. O sowipe: janmādy asya yato 'nvayād itarataś cārtheṣv abhijñaḥ svarāṭ (SB 1.1.1). Nisin ti Otito to gaju yi ni orisun gbogbo iseda yi, lehin na kini aami re? Bhagavata sowipe ogbodo wa laaye. Koi ti ku. Ogbodo wa laaye. bawo? Anvayād itarataś cārtheṣu. Gege bi mose wa laaye, eyin na wa laaye. Sugbon mio mo ara mi, aduru irun wo lowa lara mi. Mosin sowipe ori mi leleyi. Sugbon tinba bere lowo enikeni, " Se mo aduro irun melo lowa lori ara yin?" Iru imoye bayi o kinse imoye gidi. Sugbon Eledumare, Bhagavata sowipe o mo gbogbo nkan daju daju. Mo mowipe mon jeun, mio mo bi ounje ti monje sen fun eje ninu ara mi ni iranlowo, Bonse yipo, bonsen sise, bosen son ninu isan ara mi. Mio mo nkankan. Sugbon Olorun mo gbogbo awon nkan wanyi - gbogbo kooro iseda aye yi lomo nkan ton sele. Nitorina Bhagavata ti salaaye wupe, otito to gaju yi, lateni ti gbogbo nkan ti wa, O gbo wa laaye. Ogbodo mo nipa gbogbo nkan. Abhijñaḥ, abhijñaḥ itumo re niwipe o mo nipa gbogbo nkan. ele bere pe " Lehin na toba jepe Oun lo l'agbara ju, lo l'ogbon ju, o daju pe lat'elomi loti ko..." Rara. Awa sowipe toba jepe lat'elomi loti ko awon nkan wanyi, lehin na Olorun ko loje. Svarāṭ. lesekese. O wa fun ara re. . jñāna-yoga niyen. Ikeeko, iwa wo .. E gbiyanju lati monipa iwa Eledumare lat'eni toje pe gbogbo nkan ti wa. Wanti salaaye ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Nitorina Śrīmad-Bhāgavatam ni jnana-yoga ati bhakti-yoga paapo. Beeni. Itumo ilana Jñāna-yoga yi ni lati sewaadi nipa Otito to gaju yi tabi lati ni oye nipa Otito Mimo lat'ona imoye. Nkan ton pe ni jnana-yoga niyen. Bhakti-yoga ni t'awa. itumo Bhakti-yoga niwipe, Ilana kana lowa, afojusun kanna. Eyan kan sin gbiyanju lati de ipo to gaju lat'ona imoye ikeeko, Elomi sin gbiyanju lati fokanle Oluwa, awon iyoku awon bhakta sin gbiynaju lati sise ninu ise Eledumare kobale farahan. Ilana kan wa lati ni oye nipa bi eto yi sen gunke, ikeji ni lati mo bonsen sokale. Gege bi okunkun, teyin ba gbiyanju lati mo nipa bi orun sen jade, lati ori oko afefe teyin ni tabi sputniks, eyin kan ma yipo lori afefe, eyin o le ri nkankan. Sugbon pel'ona ton sokale, nigbat'orun ba jade oma ye yin lesekese. Ona ton gunke - pel'agbara mi, ona lati nkan timo le ri. Gege bi baba sowipe awon okunrin o le wa laaye tayeraye. Mo gba bee. Nisin tinba fe sewaadi lori boya okurin eda le wa laye tayeraye, lati wo gbogbo awon okurin laye yi, asiko toma gba tipo ju. Sugbon teyin ba gba imoye lat'eni to gaju yin lo, pe okurin o le wa laye tayeraye, imoye yin ti daju niyen.

Beena:

athāpi te deva padāmbuja-dvaya-
prasāda-leśānugṛhīta eva hi
jānāti tattvaṁ bhagavan-mahimno
na cānya eko 'pi ciraṁ vicinvan
(SB 10.14.29)

Nitorina wan sowipe, "Oluwa mi, eni toba ti gba oreofe die lowo yin, ole ni oye kia kia. awon ton sin gbiynaju lati nii oye na pelu ise owo won, wanle yipop bayi fuin aimoyer odun, kole ye won lai lai. Kole ye won lai lai. Ibanuje loma gba okan won. Oh, kos'Olorun. Otan. Ti Olorun o ba wa, bawo ni gbogbo awon nkan wanyi ti wa? Olorun n'be. Bhāgavata sowipe Vedānta says janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). lat'Oluwa ni gbogbo nkan ti jade. Nisin agbodo sewaadi lori bose jade. Wanti salaaye re na, boseje, ilana to wa, basele mo. Vedānta-sūtra niyen. Imoye to gaju nitumo Vedānta. Imoye nitumo Veda, to gaju nitumo anta. Beena itumo Vedanta ni imoye to gaju. Olorun ni imoye to gaju.