YO/Prabhupada 0664 - Void Philosophy Is Another Illusion. There Cannot Be Any Void



Lecture on BG 6.13-15 -- Los Angeles, February 16, 1969

Tamal krsna: bhagavad gita, sowipe idekun owun iyonda aye ko tu mosi wipe anwonu aye ti ofo ti o je nkan kan adaparo

prabhupada:beni.idekun owun iyonda aye ko tu mosi adaparo nitoriwipe e mi o daparo,emi okan ni mi toba jewipe mo daparo,bawo wani idagbasoke ara mi see je e mi o je adaparo, irugbin ni mi, bi antinse gbin irugbin ni ile yi oo gbooro/dagba si igi ti o tobi tabi ohun igbin to tobi bekan na owun igbin .ni baba ngbin si ile-omo ti iya yi o si tobi/dagba bi igi, ara yi shii wa ni bee ibowa ni adaparo wa wa Ahaṁ bīja-pradaḥ pitā (BG 14.4). ninu apa merinla e o ri wipe krsna ni ofun wa ni atileba irugbin. ninu ile-omo ti aye iyonda yi, beee nor ni opolopo ngbe oro ibi jade ninure ole jiyan nipa re,nitoripe iran gaan koyato si eyi ti anfi see ise ninu ile aye wa a ti ri wipe baba fun irugbin sii inu ile-omo ti iya be nor ni iya, yio toojuu omo/irugbin titi yio fi dagba si ara kosi oro adaparo, ti irugbin ba je adaparo,bawowani agbakale ara ti o dara see je nirvana tumosi wipe aa o gbodo gba ara ile yonda aye yi mo mase gbiyanju lati je ko di adaparo,oro isokuso imiiran ni yen adaparo, Iwo o kin shee adaparo,adaparo tumosi wipe lati see ara aye iyonda yi ni adaparo ara yi ti okun fun itonule ibanuje, gbiyanju lati se agbekele ara ti e sinu emi ara osenshe.Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6). awon nkan yi wa nibe, nitorina ani lati ni oye ki ni ishoro ile-aye, kini,bawoni awa mase lo foomu eda eniyan yi okoo yi ko si ninu gbogbo ori-lede aye igbakale yi nikan ni o soro nipa isoro aye ati itumo iye aye eyi lonje aiji ronu lori krsna. tesiwaju

Tamala krshna:kosi adaparo ni ibi Kankan ninu esheda ti olorun,afi ti idaduro ti aye-iyonda

prabhupada: adaparo,se ori ni ibi Kankan, tabi ni inu ile,tabi ninu aye,oo ni ri ohunkankan ti o daparo lori aye,kosi adaparo,ni orun, kosi adaparo ninu afefe, kosi adaparo,ninu omi kosi adaparo ninu ina,kosi adaparo-ibo wa ni ama ti ri adaparo? ibo lo ma ri adaparo? imoye adaparo yi je iruju miran.kosi adaparo ofo kankan