YO/Prabhupada 0707 - Those Who Are Not Enthusiastic, Lazy, They Cannot Advance in Spiritual Life



Lecture on SB 3.26.30 -- Bombay, January 7, 1975

Odo metalokan wa. Ninu Bhagavad-gita Krsna sowipe paras tasmāt tu bhāvaḥ anyaḥ: (BG 8.20) "bhava, iseda imi tun wa." Kinitumo iseda? Sarveṣu naśyatsu na vinaśyati: "Nigbati ile aye yi, ba tan, iyen loma seku. Kole paare." Apeere to po ga wa. Gege bi omi ninu ile gbigbe. Nigbami ele r'omi ninu ile gbigbe. Awon eranko man sa tele iru omi bayi, sugbon kos'omi kankan. Nitorina erank na ma ku. Sugbon awon eda eyan awa o gbodo dabi eranko. Wan gbodo ronu. Wan l'opolo. Wan le bere sini ronu dada ton ba a awon iwe mimo wanyi t'Olorun ti fun wa. Eda kanna ni Vyāsadeva je pelu Krsna, beena oti funwa ni awon iwe mimo Veda. Nitorina ni oruko re seje Vedavyasa, eda kana pel'Olorun, Vedavyasa. Mahā-muni-kṛte kiṁ vā paraiḥ. Kosejo pe eyin fori ro. E tele Vyasadeva ninu ile eko awon akeko. Narada Muni l'akeko Vyasadeva. Vyasadeva ni akeko Narada Muni. Beena ninu eto parampara yi, taba gba imoye, imoye toje pipe niyen. Beena agbodo gba bee. Niścayātmikā.

Nitorina Rupa Gosvami sowipe ale ni ilosiwaju ninu et mimo, sugbon nkan t'alakoko ni utsaha. Utsāhāt.Igbiyanju nitumo Utsāha Beeni, Krsna sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Teba sise dada lori oro yi ma gba bee, bi Krsna se so." Krsna sowpe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65), agbodo se, pel'anfanni. "Beeni, Moma ronu nipa Krsna nigbogbo igba." Man-manāḥ. Kṛṣṇa sowipe. Man-manā bhava mad-bhaktaḥ, " Oye ke di olufokansi simi." Beena agbodo l'anfaani gan, " Beeni, mofe d'olufokansi Krsna." Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī. Krsna sowipe " E gbadura simi." beena agbodo l'anfani gan lati s'adura si Krsna, kase maṅgala-ārātrika, ka ji l'aaro kutu. Igbiyanju ni gbogbo eleyi, utsaha. Awon eyan ti o l'anfani, ton yoole, kosi bonsefe ni ilosiwaju ninu eto mimo yi. Kama sun nikan, kolese se. Agbodo gbiyanju gan. Utsāhād Utsāhād. Isuru nitumo Dhairya, Konsepe " nitoripe mo tin gbiyanjugan ninu eto mimo yi.." Beena et de ipo to gaju, Sugbon teyin o ba leni suru pe " Kilode timio ti di pipe? Nigbami maya sin funmi nipaa?" Beeni. Bose ri niyen. Nkan wanyi ma sele. Kole paare. Niścayāt. Dhairyāt. niścayāt Nigbati Krsna ba sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66), nisin moti fi gbogbo nkan sile, mio ni'se imi Ju kin sise fun Krsna. Beena, timo se beere, niscaya niyen, Krsna ma funmi ni idaabo." Niscaya niyen. Ema jeki ibanunje mu yin. Eyan eke ko ni Krsna je. O sowipe, ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi.