YO/Prabhupada 0712 - Krishna dictated 'You Go To the Western Countries. Teach Them'



Lecture on SB 1.16.22 -- Hawaii, January 18, 1974

Teyin ba wa sinu imoye Krsna, aye yin ti di pipe. teyin basi ni oye imoye, lehin igba teba fara yi le - tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9), kosejo ara imi. Beena egbe imoye Krsna leleyi. Ise awon ton toju wa bi guru, baba, ijoba lati wo pe awon ton toju wan gba imoye Krsna yi dada. Ise to wa niyen. Nigbati wan o ba sise yi.. Awa o ni ise imi. Ni Vrndavana mole gbe nibe ni alaafia, yara mehi siwa n'be ni ile-ajosin Radha-Damodara sugbon nitoripe imoye Krsna yi wa... Sise fun Olorun nitumo imoye Krsna. Imoye Krsna niyen. Beena Krsna si sowipe " O joko sibi l'alafia. Rara, losi awon ilu geesi. Ko won." Beena imoye Krsna niyen, egbiyanju ke konipa imoye Krsna yi, lati ko awon eyna tio ni imoye yi. Nkan to daju niyen. Vyasadeva ri maya yi, tabi okunkun.. Yayā sammohito jīva. Gbogbo agbaye pelu awon eda lon wa ninu idimu maya. Yayā sammohito jīva ātmānaṁ tri-guṇātmakam (SB 1.7.5). Wan rope ara wan lonje, awon oniranu, ode. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke (SB 10.84.13). Eni toba rowipe " Ara mi nimo je," bi ologbo tabi aja loje Kobaa woso to da, ologbo tab aja loje.Otan. Bi eranko loje. Nitoripe koni oye kankan nipa eni toje. (segbe) Mase bayi. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke... (segbe) Iwo o le joko bayi? Beeni. Sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ. Nkan ton sele niyen. Awon eyan rowipe, " Ara mi nimi," gege bi awon ologbo at'aja. " awon nkan toti ara mi jade, emi nimo ni won." Sva-dhīḥ kalatrādiṣu. " Moti ni asepo pelu awon obirin. Nitorina iyawo mi ni, iru nkan bayi. Omode, na -nkankan. Wan o mo nkan temi yi je, ara won nikan lon mo. " Beena wan ti bi ara wa si orile-ede kan. Nitorina latibe nimo ti wa. Bhauma ijya-dhīḥ. Won sin lo gbogbo agbara won fun ilu na sugbon asise loje ton fi bi nibe. Wanti salaaye gbogbo e ninu Bhagavata. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ (SB 10.84.13). Ile nitumo Bhauma. Nkanton sele niyen. Itanraeni leleyi. Koni nkankan pelu awon nkan wanyi. Nigbataba mo wipe " mio ni nkankan se pelu awon nkan wanyi, tabi ara mi, tabi ilu yi, iyawo yi, awon omode yi, itanraeni ni gbogbo e. Ominiran ni yen.