YO/Prabhupada 0716 - We Must Understand by Knowledge What is Krishna



Lecture on CC Madhya-lila 8.128 -- Bhuvanesvara, January 24, 1977

koko oro towa niwipe agbodo ni oye nipa Krsna. L'ojo tokoja enikan bere, "kini itumo Krsna?" Eniton fa gbogbo eda mora nitumo Krsna Afi ti gbogbo wa bani ifarasi Olorun bawo lose fe j'Olorun? Beena aye Vrndavana niwipe Krsna wa, Krsna sokale wa lati fihan nkan t'olorun je Aye abule niti Vrndavana. Awon ara abule, awon oloko, maalu, omo-maalu - Vrndavan niyen. Kon se ile bi New York, London; Abule loje, sugbon Krsna ni koko oro nibe. aye Vrndavana niyen. Awon gopi, awon omo-obiri abule na, ati awon oluso maalu omo okurin, omo-okurin abuloe na niwon. Nanda Maharaj ni Olori abuloe yi, oloko. Beena, awon agba ati awon gopi agba, Mama Yasoda ati awon ore re - gbogbo wan lonni ifarasi Krsna. Ile aye Vrndavan niyen. Awon eyna yi o tie mo eni ti Krsna je. Kon se pe wan ka awon Veda, Purana, Vedanta lati le mo Krsna. Sugbon pelu ife t'okan won fun Krsna. Beena svābhāvika ākarṣaṇa Lasiko yi awa ni ife kankan fun Krsna; nitorina agbodo ni oye nipa eni ti Krsna je. Kṛṣṇa tattva vettā niyen. Beena kilode teyan feni ifarasi Krsna afi Krsna bani gbogbo amuye to dara? Ifarasi... Ninu ile aye yi, Awa ni ifarai Olowo okurin, tabi alagbara okurin. Okurin tab'Obirin. Gege bi alakoso ijoba ni ile isofin wa, obirin loje, sugbon o lagbara gan, Asi feran re; asi man soro nipa re. Awon eto fun ifarasi wanyi, Parasara Muni ti pe won ni bhaga. Ola nitumo Bhaga. Awon Ola wanyi.. Teyan ba lowo, Olola loje. Teyan ba lagbara, awaon eyan ma ni ifarasi. teyan pataki ba wa, teyan ba lewa, teyan ba keko... Awon nkan ifarasi leleyi. Gege na tawa ba ko nipa Krsna ni pipe, Ema riwipe ni itan gbogbo agbaye yi, koselomi to lowo ju Krsna lo, Koseni to lagbara ju Krsna lo, koseni to lewa to Krsna, koseni to keeko ju Krsna lo. Teba si ka awon iwe yi, ema ri wipe awon ola mefa wanyi wa ninu Krsna; nitorina lon sen pe ni Bhagavana. Ola nitumo Bhaga, enito ni nitumo van. Itumo Krsna niyen, pe gbogbo eyan ni ifarasi nitoripe oun loni gbogbo awon ola mefa wanyi ni pipe. Ijuwe Krsna leleyi. Beena awa o gbodo gba enikeni bi Bhagavan. Agbodo wo boya awon ola mefa wanyi wa.