YO/Prabhupada 0725 - Things Are Not Going to Happen so Easily. Maya is Very, Very Strong



Lecture on SB 7.9.22 -- Mayapur, February 29, 1976

nkan ton pe ni ile aye eda leleyi, teyan ba ni oye.. awon eranko, kole ye won pe won jiya. awon ologbo at'aja, won rowie on gbadun. sugbon awon eda gb odo wa sori ipo yi lati ri wipe " ni otooro ile aye tan gbe o da. Akoko aye yi ti pa gbogbo wa l'oan orisirisi." Niṣpīḍyamānam. teyan ba l'ogbon nigbana lodi eda eyan. Bibeko eranko loje. toban rowipe gbogbo nkan lo da... opolopo awon eyan lon rowipe " gbogbo nkan lo da." Ninu ile aye awon elede gan, wan rowipe " o da bayi." Aimokan yi ma lo titi nitoripe, eranko loje. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma-ijya-dhīḥ (SB 10.84.13). Nkan ton sele leleyi. Ātma-buddhiḥ, tri-dhātuke. Ara eda yi toje pe kapha, pitta, vayu lon fi se. sugbin gbogbo eyan rowipe ara won lonje." Nkan ton sele ninu gbogbo agbaye niyen. Awa taje olofokansi ninu egbe inoye Krsna yi, awa sin lo lati ile kan sikeji, Edakun sa, ara yin kole je." Sugbon won o fe mo " Ara mi nimi" john ni mi." Okurin geesi nimi, Omo ilu America nimi, omo ilu India nimi. E sowipe Ara yi ko ni mi. Nkan to le gan fun won leleyi. Lati tesiwaju nhinu egbe imoye Krsna yi agbodo ni isuru, ati ifaramo. sugbon Caitanya Mahāprabhu ti p 'ase,

tṛṇād api sunīcena
taror api sahiṣṇunā
amāninā mānadena
kīrtanīyaḥ sadā hariḥ
(CC Adi 17.31)

awon ton ti gba iwaasu imoye Krsna yi bi ise, oye kan mo wuioe awon nkan o ni rorun titi lo Maya l'agbara gan. sugbon agbodo tiraka pelu maya. Ogun to wa niyen pelu maya. Maya ti fi gbogbo awon eda labe re, asi fe ki awon eda wanyi jade ..iyato to wa niyen. Kālo vaśī-kṛta-visṛjya-visarga-śaktiḥ. śakti yi, visarga-śaktiḥ, lagbara gan O lagbara gan sugbon o wa labi idari Krsna. Mayādhyakṣeṇa prakṛtiḥ sūyate sa-carācaram (BG 9.10). Prikrti yi sin sise dada, On sise gan, lesekese ti sanmo bawa, ni iseji keji orun ti jade. Ninu isejukan sanmo le tun jade pelu ojo tole ba nkan je. O le sese. Awon ise maya niyen. Sugbon o si wa labe agbara Olorun. Ale ri Orun yi, bose tobi to, os tobi ju ile agbaye yi lo, seyin sin ri bosen jade kiakia lojojumo. Osin saree gan. Bawo losen sele? Yasyājñayā bhramati saṁbhṛta-kāla-cakro govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ... (Bs. 5.52). Labe idari Govinda leleyi tin sele. Nitorin lose je vibhu. Alagbara loje. Awa o mo bose lagbara to. Nitorina lasen gba awa oniranu bi Olorun. Awa o mo eni t'olorun je. Ode niwa. Andhā yathāndair upanīyamānās. Afoju niwa, afoju imi lon fona han wa: "Olorun nimi. Olorun ni e. Olorun ni gbogbo wa," Olorun i ri bee. Nibi Olorun ti so eni to je .. Kālo vaśī-kṛta-visṛjya-visarga-śaktiḥ: "Oun lon toju akoko agbaye yi ati agbara iseda." Olorun niyen.