YO/Prabhupada 0728 - One Who Understands Radha-Krishna Lila as Material, They Are Misled



Lecture on CC Adi-lila 7.5 -- Mayapur, March 7, 1974

Lati Krsna ni Agni tiwa. Lati Krsna ni Mahi, ile ti wa. Agni, mahī, gagana, sanmo lati Krsna loti wa. Ambu, omi lati Krsna loti wa. Agni mahī gaganam ambu... Marut, ategun, lati Krsna loti wa. Nitoripe lati Krsna ni gbogbo nkan wanyi ti wa, ko yato si Krsna. Sugbon teyin ba too ategun, omi, ina ati ile yi wo eyin o le sowipe nitoripe ategun ati omi wa lati Krsna, mole wa ninu ategu atbi omi, nkankann no loje." Awa wa ninu ategun sugbon taba rowipe ategun at'omi oe nkankana lonje, timo fosinu omi, nkan tio da niyen. Krsna ni ategun, omi ati ile yi, ni otooro Ina na ni Ksan, nitoripe agbara Krsna ni gbogbo won.

Gege bayi teyin ba gbiyanju alti ni oyr nipa panca tattva, śrī-kṛṣṇa-caitanya prabhu-nityānanda, śrī-advaita gadādhara śrīvāsādi-gaura-bhakta-vṛnda... Panca-tattva leleyi: Śrī Kṛṣṇa Caitanya, Śrī Nityānanda, Śrī Advaita, Śrī Gadādhara, ati Śrīvāsādi. jiva tattva nitumo Śrīvāsādi Awon jīva-tattva, śakti-tattva, viṣṇu-tattva, tattva na ni gbogbo won. beena Panca tattva, Sri Krsna ni tattva to gaju, Krsna. Śrī-kṛṣṇa-caitanya, rādhā-kṛṣṇa nahe anya. awa s'aadura si Rādhā-Kṛṣṇa. Beena Śrī Kṛṣṇa Caitanya ni Rādhā-Kṛṣṇa papo. Śrī-kṛṣṇa-caitanya, rādhā-kṛṣṇa nahe anya.

rādhā-kṛṣṇa-praṇaya-vikṛtir hlādinī-śaktir asmād
ekātmānāv api bhuvi purā deha-bhedaṁ gatau tau
caitanyākhyaṁ prakaṭam adhunā tad-dvayaṁ caikyam āptam...
(CC Adi 1.5)

Rādhā-Kṛṣṇa... Kṛṣṇa l'olorun to gaju. Ti Krsna bafe gbadun..Onigbadun Bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Oun ni onigbadun. Beena to ba fe gbadun, igbadun aye yi ko niyen. Igbadun mkimo niyen - agbara mimi t'aye yi ko Nitoripe Krsna ni Olorun to gaju, nitorina agbara mimo re lon gbadun. Nkan aye yi ko ni Rādhā-Kṛṣṇa līlā. Awon eyan ton rowipe Rādhā-Kṛṣṇa līlā je nkan aye yi wan ti sonu. Krsna o le gbadun nkan aye yi. Teyin ba sowipe " lojujumo a wan riwipe eyin fun Krsna ni prasada, efo, iresi. nkan aye yi gbogbo eleyi. rara nkan aye yi ko. Imoye gidi to wa niyen. Bawo ni kose je nkan ay yi? acintya leleyi, kole ye wa. Krsna le so nkan aye yi di mimo, osi le so nkan mimo di t'aye yi. Agbara re tio le ye wa leleyi, acintya-sakti. Afi teyin ba gba acintya-sakti yi, eyi o le mo nipa Krsna. Acintya -sakti.