YO/Prabhupada 0737 - First Spiritual Knowledge Is This - 'I Am Not This Body'



Lecture on BG 4.1 -- Bombay, March 21, 1974

Prabhupada: ara yi yato si ara won. Nkankan l'emi wa je. Emi yin ati temi nkankan na loje. Sugbon ara omo ilu Ameriaca leyin ni, t'omo ilu India ni temi. Iyato to wa niyen. Gege b'ase wo aso toyato. Aso mi yato si teyin. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vi. Bi aso na ni ara wa seri. Gege na imoye wa talakoko niwipe, " ara mi ko nimi," Lehin na imoye mimo wa le bere. Bibeko kosi basele ni imoye mimo. Yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ (SB 10.84.13). Eni to ronu pe ara mi nimi, " Ara mi ni moje, asiwere loje, eranko. Otan. Iru iwa eranko to sele ninu agbaye yi leleyi. omo-ilu America nimi, omo-ilu India nimi, brahmana nimi, ksatruay nimi. Iranu leleyi. Egbodo koja iru nkan bayi. Lehin na lele ni imoye mimo. bhakti yoga niyen.

māṁ ca yo 'vyabhicāreṇa
bhakti-yogena sevate
sa guṇān samatītyaitān
brahma-bhūyāya kalpate
(BG 14.26)

Ahaṁ brahmāsmi. Nkan ta fe niyen. Beena Lati ni oye nipa eto yoga yi, bhakti yoga... Nitoripe afi pelu bhakti yoga nikan lale wa sori ipo mimo. Ahaṁ brahmāsmi. Nāhaṁ vipro... Caitanya Mahāprabhu sowipe, nāhaṁ vipro na kṣatriya... Kini sloka na?

Olufokansi: : Kibā vipra kibā nyāsī...

Prabhupada: " brahmana ko nimi, ksatiya ko nimi, vaisya ko nimi, sudra konimi. brahmacari ko nimi, grhastha ko nimi, vanpratha ko nimi..." Nitoripe awujo Veda wa lori varna ati asrama. Beena Caitanya Mahaprabhu ti fi gbogbo awon nkan wanyi sile: Mio ni nkankan se pelu awon nkia wanyi." Ki wani ipo yin? Gopī-bhartuḥ pada-kamalayor dāsa-dāsānudāsaḥ: (CC Madhya 13.80) " Emi ni iranse tayeraye eniton toju awon gopi." Krsna niyen. O si se waasu: jīvera svarūpa haya nitya-kṛṣṇa-dāsa (CC Madhya 20.108-109). Idanimo wa niyen. Iranse tayeraye ti Krsna. Nitorina awon iranse ton ti sa fi Krsna si sile lon ti wa si ile aye yi Lati mu won pada ni Krsna sen wa Krsna si sowipe,

paritrāṇāya sādhūnāṁ
vināśāya ca duṣkṛtām
dharma-saṁsthāpanārthāya
sambhavāmi yuge yuge
(BG 4.8)

Krsna man wa. Aanu re si po gan fun wa. Eje ka mu wiwa re ni pataki, osi ti fun wa ni iwe Bhagavad-gita, teba ka dada, ile aye yin ma ni ilosiwaju. Egbe imoye Krsna niyen. Kon se egbe iranu. Egbe ton sewaadi bi t'oni sayensi. Ni awon ilu lehin India bi Europem America awon eyan tin mu ni pataki. kilode ti awon omo-okurin India yi o le se? Kilode? Ko da bayi. Eje ka fowo papo, ka bere egbe imloye Krsna yi dada, kasi ran awon eyan lowo. Ise wa niyen. Awon jiya nitoripe wan o ni imoye. Gbogbo nkan ti wa nisin,pipe. Awon ole ati odaran lon toju nkan aye yi nisin. E mu oro yi k'aye yi di pipe ninu imoye Krsna kesi fun ile aye yin ni aseyori. Ese pupo. Hare Krsna.