YO/Prabhupada 0743 - If You Manufacture Your Program of Enjoyment, Then You Will be Slapped



Morning Walk -- April 7, 1975, Mayapur

Rāmeśvara: awon eyan gbadun, sugbon toba je ore wa..

Prabhupada: Lato gbadun wan si gba igbati, nkan meji. Seti ri bayi? Ti awon omode ban gbadun nigbami baba wan ma gbawon leti. Kilode?

Puṣṭa Kṛṣṇa: Aigboran. Wan le se nkan tio da fun ara won.

Prabhupada: Beena ele gbagbadun ile aye yi bi baba wa se fe. Ise ifarasi Olorun niyen. Lehin na ele gbadun. Bibeko wan gba yin leti.

Trivikrama: igbadun eke.

Prabhupada: Beeni. teyinh ba da igbadun yin sile wan sil gabi leti. Sugbon teba gbadun bi baba wa sefe, koni si wahala. Krsna sowipe, " E gbadun aye yin. A dabee" Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī. E gbe l'aalafia. E ronu nipa mi. E gbadura simi." nkan t'awa ti salaye niyen, " Ewa sibi keronu nipa Krsna." Igbadun to wa niyen. Wan o fe. Wan fe moti. Wan fe ni imo ako ati abo. Wanfe jeran. Nitorina wan gbudo gba ifoti yi. Fun igbadun lonse da ile aye yi, sugbon egbadun bosefe ke gbadun. Lehin na ele gbadun dada. Iyato laarin awo orisa at'esu leleyi. Awon esu fe gbadun bon se fe. awon orisa sin gbadun ju wan lo nitoripe wan gbadun b'Olorun se fe.

Jagadisa: Kilode ti Krsna se da awon igbadun ese wanyi? Kilode ti Krsna se da awon igbadun ese wanyi?

Prabhupada: Igbadun lasan?

Jagadisa: Igbadun t'elese bi oti mimu...

Prabhupada: Krsna ko le daa le> Eyin le daale fun ara yin. Krsna ko lo sowipe ke jeran, sugbon eyin le daile iperan yi sule, nitorina lesen jiya.

Brahmānanda: Sugbon igbadub wa teyin le ni lati awon igbadun elese wanyi.

Prabhupada: igbadun wo? (erin)

Brahmananda: awon eyan imi fe gbadun oti mimu,

Prabhupada: Beeni. Lehin na wan ma jiya . aimokan leleyi. Lesekese teyin ba ni igbadun iye ara yi, ti ibajade na o ba da. tosi je ese.

Ramesvara: e ti salaaye ni apa iwe kerin pe tawa ba gbadun dun taba kere, ama ni aisan bayi taba darugbo.

Prabhupada: Beeni. Nibi itumo ile aye yi niwipe, lesekse teba ti awon ofin wanyi segbe, ema jiya. Nitorina varṇāśrama-dharma ni ibere ile aye eda. ni ibeere. Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭam (BG 4.13). Olorun ti da awon nkan wanyi. Teyin ba mu varnasrama dharma yi ni ataki, ile aye yi ma wa ni pipe.