YO/Prabhupada 0744 - As Soon as You See Krishna, Then You Get Your Eternal Life



Lecture on SB 7.9.53 -- Vrndavana, April 8, 1976

baba Prahlada Maharaja si da isoro to po fun sugbon o gbagbe Krsna. Ife ti duro Nitorina ni inu Krsna se dunsi, prito'ham. Prīto 'ham. Prahlāda bhadraṁ (SB 7.9.52). Mām aprīṇata āyuṣman (SB 7.9.53). Āyuṣman, ibukun. Nisin ele wa laaye fun asiko to pe tabi tayeraye, Āyuṣman Iwonba aye nitumo Ayus. Teyan ba summon Krsna.. Mām upetya kaunteya duḥkhālayam aśāśvatam, nāpnuvanti. Duḥkhālayam (BG 8.15). Tawa ba wa ninu ile aye yi, duḥkhālayam aśāśvatam loje. awon nkan isoro nikan lo wa ninu e, sugbon nigba kanna fun igba die lowa. tabe tie gba ipo tio da gan... gbogbo eyan lofe wa laaye. Arugbo gan o fe ku. A los'odo dokita, lati gba ogun tole jeko wa laaye. Sugbon kole gbe ju boseye lo. Aśāśvatam. Ele je olowo, ele mu ogun to po, ele gba abeere lati jeke wa laaye, sugbon kolese se. Sugbon lesekese teyin ba ri Krsna, eti ni aye tayeraye. aye tayeraye lawa ni. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Awa o le ku ti ara yi ba ku. Ama gba ara imi. Aisan to wa niyen. Tein ba ri Krsna, teyin ba ni oye nipa Krsna... Teyin ba ni oye gan olaye foju ri, eti ni aye tayeraye niyen.

janma karma ca me divyaṁ
yo jānāti tattvataḥ
tyaktvā dehaṁ punar janma
naiti...
(BG 4.9)

Krsna sowipe. Egbiyanu lati ni oye nipa Krsna. lati ni oye nipa Krsna nkankanna loje pelu wipe e ri Krsna, nitoripe o si iyato. Sugbon ninu agbaye yi ele ni oy nipa nkan teyin o foju ri. sugbon ninu eto mimo, teun ba ni oye nipa Krsna, teyin ba gbo lati Krsna, teyin ri Krsna, teba Krsna sere, nkankan loje. Nkan to je pipe niyen. Kosona meji.

Teyin ba nioy nipa Krsna, divyam teyin ba mo wipe Krsna o jo wa: Ko ni ara bi t'awa, Krsna o le ni ibauje, gbogbo igba ni inu re man dun - awon nkan keker wanyi, Teyin ba mo wipe iwa Krsna niyen - lesekese leyin ma ye niyan lati padf as'odo metalokan, si ile. Imoye Krsna yi dara gan. Krsna gan sin salaaye fun ara re, toba si dayin loju, "Beeni, nkan ti Krsna so daju." Gege bi Arjuna se sowipe, sarvam etam ṛtaṁ manye yad vadasi keśava: (BG 10.14) "ounkoun teyin ba so moti gba. Lai dikun,... Sarvam etam ṛtaṁ manye: "Ounkoun teyin baso, mo gbabee, Krsna niyen, Krsna ti so nkan imi , nkan imi lo ye mi. Ema lobayi titi aimoye odun, kolese se. Egbodo ni oye bi Krsna se salaaye. itprina lasen fun yin ni Bhagavad-gita gege boseje. Imoye to daju.