YO/Prabhupada 0883 - Ema lo asiko yin ni ilokulo lori eto oro aje, iranu leleyi



Lecture on SB 1.8.21 -- New York, April 13, 1973

Krsna si feran lati ni asepo pelu awon elesin re bi baba tabi iya. Ninu ile aye yi, awa si fe gbiyanju lati ni abasepo pelu Eledumare bi baba, sugbon Krsna fe d'omo wa. Nitorina nanda-gopa (SB 1.8.21). Osini idunnu repete lati d'omo elesin Awon eyan lasan fe ki Olorun je baba si wan, sugbon iyen o dun mo Krsna. Teyan ba je baba, nigbogbo igba niwan bere lowo re " e funmi ni tibi, efunmi ni tooun>" Se ri bayi. Krsna sini agbara to po lati fi pese fun wa. Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. O le fun gbogbo eyan bose fe si. Osin nfun awon Erin lounje, ati awon kokoro na. Kilode tio se ni fun awonn eda eyan? Sugbon awon asiwere wan yi o mo. Wan sise lati aro daale lati wa ounje. toba de losi ile-ijosin, lati lo bere ounje nani,isoro kan toni niyen, otan. awon eda je omo eda to lowo ju sugbon wanti isoro ounje sile, aimokan leleyi. On rowipe " ti mio ba yonju eto ounje mi, ti mio ba wa oko mi lataaro daale ( on se ohu oko, erin) awujo iran. isoro ounje, Isoro ibi t?'ounje wa Krsna le pese . Toba le fun awon erin ni Africa lounje aimoye awon erin to wa ni Africa, wan sin jeun.

Bhagavata ti sowipe e ma losi asiko yin ni ikokuko pelu eto ounje. Ema lo aisiko yin nilokulu. Tasyaiva hetoḥ prayateta kovido na labhyate yad bhramatām upary adhaḥ (SB 1.5.18). ema lo asiko yin ni ilokulo lori eto oro aje, iranu leleyi. momope inu awi ma baje, Kini Swamiji so? sugbon otot oro to wa niyen. Iranu imi leleyi kasowipe eyin ni baba to lowo gan, pelu ounje to po nibo ni isoro oro aje wa? Iranu leleyi. Kosi isoro kankan. Teyin ba mowipe baba mi okurin to lowo ju ni ilu yi nibo ni isoro oro aje wa? Kini ipo towa. Awa o ni isoro kankan. gbogbo nkan ti wa. Pūrṇam adaḥ pūrṇam idaṁ pūrṇāt pūrṇam udacyate (Īśopaniṣad, Invocation). Gbogbo nkan ti wa. Se f'omi. Awon okun wa. E fe omi to mo. Eyin o lewse. Omi okun po, sugobn kos'omi, ele gba oranlowo lodo Krsna. A so omi na di afefe. toba ti ra asi dun lenu. Bibeko eyin o le fowo kan. Gbogbo nkan wa labe idari re - omi, ina, oru. Pūrṇāt pūrṇam udacyate, pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam evāvaśiṣyate (Īśo Invocation). awan nkan re o le tan. E kan teriba ade fun yin O le yeyin.

Awon eyan ninu imoye Krsna wan o ni isorokan kan. Krsna ma pese ounkoun tonba fe. Ni Los Angelese awon aladugbo wa ni itara si wa, pe " eyin o kin sise, eyin o ni isoro kankan, sugbon esi loko merin. Esi jeun dad. " Bawo loseje?" Wan beere bayi lowo awon elesin wa. Otooro too wa nien. Awa na owo to po, asi ni awon ile-ajosin to po. awan na too $70,000. Talo fun wa? Bakanna tabi keji, asin rigba. Kosi isoro kankan. E sise fun Krsna o tan. Gbogbo nkan tiwa. Idanwo to wa niyen.