YO/Prabhupada 0706 - Real Body Is Within



Lecture on SB 3.26.29 -- Bombay, January 6, 1975

Beena anfaani toye ka ni ni basele ni ominira lati igbese aye yi, kasi pada si ipo mimo. Anfanni toye ka ni ninu ara eda eyan yi. awon ologbo ati aja, won o ni iru opolo bayi. Kosi bonsele se. ara ile aye yi ati iye ara toni te won lorun. Sugbon ninu ara eda anfanni wa lati ni oye pe iye ara wanyi, ati ara wa eke ni gbogbo e je, tabi fun igba die - nitori pe ara gidi mi koleleyi. Ara t'alakoko mi wa ninu ara ile aye yi. Ara eda mimo niyen je. Asmin dehe dehinaḥ. Dehino 'smin, tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13), asmin dehinaḥ. Beena ara mimo wa ni ara gidi tani, sugbon ara eda yi ti bo. Wanti salaaye ni orisirisi ona ninyu iwe Bhagavad-gītā. Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22). Ara eda yi dabi aso. Aso.. Mo wo aso, eyin na wo aso ati aṣọ awọleke. Nkan pataki ko leleyi. Nkan tose pataki ni ara towa ninu aso yi. Beena, ara eda yi je idaabo fun ara mimo tawa ni lati bugamu, sugbon ara wa gidi wa ninu. Dehino 'smin yathā dehe (BG 2.13). Ara wa yi ni won pe ni deha, olori deha na ni dehi. "eni toje olohun deha yi." Ilana kini ninu Bhagavad-gita leleyi.

Beena agbudo gbiyanju lati mo bi ara yi se wa sinu iseda aye yi, idaaabo ara mi, ara mimo, ahaṁ brahmāsmi ? " Beena lati ni oye nipa sayensi yi, Kapiladeva ti salaye ninu imoye Sankhya, bi awon nkan sen wa s'aaye. Lati ni oye nipa.... Nkankana: lati ni oye nipa nkan to rorun bayi pe " Ara yi ko ni mo je. Lati emi ni ara yi ti jade." Nitorina ati fun awon oni sayensi ni apenija. Wan sowipe lati ara wa ni emi ti jade. Rara. Lati ara wa ko l'emi ti jade, sugbon lati emi wa ni ara wa ti jade. odi keji loje. Awon onisayeni wanyi, wan rowipe akojopo awon nkan aye yi lo da awon nkan sile toje ki aye beere. rara. Beeko. Otooor niwiwpe emmi wa nibe. Wan rin kakiri gbogbo agbaye, brahmāṇḍa brahman. Ninu gbogbo agbaye nitumo Brahmāṇḍa. Nigbami emi yi le wa ninu ara eda kan, nigbami ninu imi. Nigbami lori isogbe aye yi, nigbami lori isogbe aye imi. Gege bayi, bi karma re se je si losen rin kakiri. Ile aye re niyen. Beena ei rūpe brahmāṇḍa bhramite (CC Madhya 19.151). On rin kakiri lai mo ibi ton lo. " kini ipinu aye yi? Kilode ti mose wa ninu ipo aye bayi, ninu ara eda yi, pelu gbogbo isoro aye yi?" Oyeka se ibeere wanyi. Nkan ton pe ni brahma-jijñāsā leleyi. Osi yeka daaun si dada. Lehin na ile aye wa ma ni ilosowaju. Bibeko koni wulo bi ara ologbo tabi aja - kosi imoye kankan, mudha. Mudha.