YO/Prabhupada 0020 - Lati ni imo Olorun ki nse nkan to rorun rara



Arrival Lecture -- Miami, February 25, 1975

Lati ni imo Olorun ki nse nkan to rorun rara.

manuṣyāṇāṁ sahasreṣu
kaścid yatati siddhaye
yatatām api siddhānāṁ
kaścid vetti māṁ tattvataḥ
(BG 7.3)

Laarin awon egbe gberun, opolopo eniyan, eyokan nse aniyan lati se ase yori aye re. Ko si eni ti o dunmo.. Daju daju won ko mo nitoto nkan ti aseyori aye je Ilaju ti ojo oni, oni kalu ku nsero, "Ti mo ba ni iyawo to dara ati oko faaji ati oju ile ti o jo ju, eyii ni aseyori." Eleyi kii se aseyori. Iyen je nkan ti o wa fun gba die. Aseyori gidi ni pe ki a ni idande lowo Maya ati wipe ile aye igbande ni bi ti ibi s'aye, iku, arugbo ara ati aisan je iriri. A nkoja lo ninu orisirisi igbesi aye ati pe awo omo eniyan je anfani lati ni igbala ninu idande ati ma yi ara pada lati ikan si imiran yi. Aiku ati alayo ti kii baje ni emi nitori wipe, o nse ipa owo ati ese Olorun, Krishna, sac-cid-ānanda,, ailopin, ayo aini pekun, oye ijinle. Oseni lanu, ninu aye asan ati igbesi aye idande a nfi ara bora bi aso lati ikan si inu imiran, sugbon awa ko ni ipinu ninu aye ainipekun ti emi nibi ti ko si ibi s'aye, ti ko si iku. Ko si sayensi na. Lojo kan oni, oniwosan ti aise deede okan wa se ipade mi. Ni bayi nibo ni eko re lati mo ni ipa ti emi, ipo iseda re? Nitorina daju daju, gbogbo aye yi ni o wa ninu okunkun. O jo won loju fun igbesi aye aadota, ogota tabi ogorun odun aye, sugbon won ko mo wipe ailopin, alayo ti kii dibaje ati oloye ijinle ni awa je, ati pe nitori eran ara yii ni a se wa ni idande ibi, iku, arugbo ara ati aisan. Eyi si nba aye lo.

Nitorina Śrī Caitanya Mahāprabhu, lati inu aanu giga re fun awon emi ti won ti padanu, O so kale wa. Olorun fun rara re na si wa. Sugbon Olorun ko nse iwon si won ju.. Olorun fi ofin sile pe, "Ni akoko se, o ni lati jowo ara re. Ni igba na Emi o se akoso re" Sugbon Caitanya Mahāprabhu s'aanu ju Olorun lo, bi o ti le je wipe Olorun ati Caitanya Mahāprabhu, je enikan naa. Nitorina lo je wipe nipa aanu Caitanya Mahāprabhu, ni afi nni oye Olorun pelu irorun. Nitorina ni Caitanya Mahāprabhu se wa nbi. E maa sin. Ko soro rara. Yajñaiḥ saṅkīrtanaiḥ prāyair yajanti hi su-medhasaḥ. Kṛṣṇa-varṇaṁ tviṣākṛṣṇaṁ sāṅgopāṅgāstra-pārṣadam, yajñaiḥ saṅkīrtanam (SB 11.5.32). E kan ni lati se ipe mantra Hare Krishna, ati nkan ki nkan ti e ba ni, e fi se s'ore fun Caitanya Mahāprabhu. O ni aanu pupo. Kii wo asise. Esin Rādhā-Kṛṣṇa soro die. A gbodo se isisn Re pelu iberu nla ati igbe gege. Sugbon Caitanya Mahāprabhu so kale wa ni pa mimo se re lati gba awon emi ti won sofo la. Pelu ise aanu kekere, yi O si ni itelorun. O si ma ni itelorun. Sugbon e o gbodo ma se aifojuto re. Nitori wipe O se alaanu pupo, iyen ko fun wa ni ominira lati gbagbe ipo re. Oun ni Olorun Eleda ti o ga julo. Nitori eyi a gbodo gbe ga pelu iyi ati ogo, bi oti see se to Sugbon ere re ni wipe Caitanya Mahāprabhu ko nka asise kun. Ati lati se isin re, lati se itenu re, ko soro rara. Yajñaiḥ saṅkīrtanaiḥ prāyair yajanti hi su-medhasaḥ. E kan ni lati se ipe maha-mantra Hare Krishna, ki e si maa jo, ati bayi ni inu Chaitanya Mahaprabhu yi o si dun si yin. O fi ona jijo ati ki korin ti o rorun julo lati ni imole Oluwa. Nitori na bi o ba ti see se to... ti o ba see se, fun wakati meerin le loogun. Ti iyen o ba si see se, bi o si je wakati merin pere, ni emefa, E se ipe mantra Hare Krishna niwaju Chaitanya Mahaprabhu, eyin yi o si se aseyori ni le aye yin. Ododo ni eyi.