YO/Prabhupada 0026 - Won a koko ran yin losi aye nibi ti Krishna wa



Morning Walk -- October 5, 1975, Mauritius

Arakunrin Indian: Swamiji, won so fun wa wipe gege bi ise wa... A ma wa si aye miran gege bi ise owo wa. Nitorina gege bi nkan ti a ti se a gbodo pada wa ni pa ase Oluwa.

Prabhupāda: O gbodo pada wa. Nyen ti di dandan. Iwo ko le yee. Sugbon gege bi kadara re o gbodo pada wa.

Arakunrin Indian: Sugbon nitorina... Nkan ti eleyi tumo si ni wipe iwo a jere nkan ti o ti ko sile. Bee ni, abi? Nitori eyi se o ro wipe...

Prabhupāda: E gba wipe ni igba ti nkan re, kaani aso yi ya, o ni lati ra aso miran. Nisinyi, aso miran ti eni lati ra a se dee de oye te ni. Ti o ba ni oye to dara, iwo a ni aso to dara. Ti o ko ba ni owo lowo, iwo o ni ri aso ti o dara wo. Ko ju bayi lo.

Arakunrin Indian: Mo fe so gbolohun kan, Swamiji, mo ro wipe orun apadi wa ninu aye nbi gan gan, nitori ibo le ro wi pe a ma ti je ere owo wa? Ese na, ere ese wa. Nibo le ro wipe a ma ti jere re? Ni orun apadi, ti ko si...

Prabhupāda: Orun apadi ni ibi ipinu ijiya.

Arakunrin Indian: Nitorina ni o se je aye yi gan gan.

Prabhupāda: Kilo se je aye yi?

Arakunrin Indian: Lori ile aye yi, rara?

Prabhupāda: Rara. O le je...

Arakunrin Indian: Lori awon aye miran?

Prabhupāda: ....awon egbe-gberun maili to jina.

Arakunrin Indian: Sugbon ko si ni bi... Orun apadi ni kan ni o wa ni ibi kan tabi prada[?] ni o wa ni ibi miran? Se e ro be, Swamiji?

Prabhupāda: Bee ni. Bee ni. Awon aye orisirisi ni won wa.

Arakunrin Indian: Awon opolopo eniyan ni won njiya ni nu aye yi gan gan.

Prabhupāda: Nitori eyi ni won a koko lo si orun apadi fun eko ki won to wa si ibi lati jiya iru igbesi aye kan na.

Arakunrin Indian: Ni igbati emi wa ba fi ara wa yi sile, se o ma lo si orun apadi tabi... Prabhupāda: Orun apadi. Arakunrin India: ...ni agbegbe tabi o ma pada wa kia kia?

Prabhupāda: Bee ni. Awon elese, awon ko le pada wa ni kia kia. Won a koko lo gba eko won ni orun apadi ni pa bi won o se jiya si. lati je ki o mo won lara ni igba na ni won a pada wa, ki won to bere si ma jiya. Bakanna ti o ba yori ni I.A.S. Ni igbana ni iwo ma di igba keji fun adajo. Wa gba eko. Igba na ni won a fun yin ni ipo adajo. Si ti e ba tile wa deede lati pada si ijoba Orun ni odo Baba loke, won a koko ran yin lo si aye nibi ti Krishna wa lowolowo, ni ibe ni o ti ma mo yin lara. Ni igbana ni e ma lo si Vrndavana gidi gan.

Arakunrin India: Nitorina, leyin iku wa...

Prabhupāda: Gbogbo eto Oluwa ni o wa ni pipe. Pūrṇam. Pūrṇam adaḥ pūrṇam idaṁ pūrṇāt pūrṇam.. (Īśopaniṣad, Invocation). Nkan ti Olorun seda re, iyen wa ni pipe.