YO/Prabhupada 0032 - Nkan ki nkan ti mo ni lati so, mo ti so ninu awon iwe mi



Arrival Speech -- May 17, 1977, Vrndavana

Prabhupāda: Bayi mi o le soro. O nre mi lara gidi gan. Mo ti fe lo si awon ibo miran bi eto Chandigarh, Sugbon mo fi eto na silé nitoripe ipo okun ara mi ndibaje gidi gan. Nitorina ni mo se pi yan da lati wa si Vṛndāvana. Ti iku ba ma de, ko sélé ni bi. Ni bayi ko si nkan titun a ti so mo.. Nkan ki nkan ti mo ni lati so, mo ti so ninu awon iwe mi. Nisinyi eé gbiyanju lati fi s'oye ki é si ma ba isè yin lô. Bi mo wa nbe tabi mi o s i nbé, ko jamô nkan kan. Bi Olorun se ngbe aye aini pékun, bakanna, omo éda na wa fun aye aini pekun. Sugbon kīrtir yasya sa jīvati: "Eniti o ba ti se isé fun Oluwa ma gbe fun lailai;" Bee na a ti ko yin bi a se nse isé Oluwa. ati pélu Olorun a si ma gbe lailai. Ile aye wa ko ni ipékun. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Ti ara yi ba paré fun igba dié, iyen o se nkan. Ara yi wa lati di alaisi. Tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). Nitorina é gbe ti ti lai ni pa si sè isé fun Olorun. E seun pupô. Awon Omo.

Leyin: Ogooo!