YO/Prabhupada 0111 - Tẹle awọn ilana, O si wa ni aabo nibikibi



Morning Walk -- February 3, 1975, Hawaii

Elesin (1): Śrīla Prabhupāda, Ibo ni enikan ti n nianfani ase re?

Prabhupada: Guru, Oluko ni alase.

Elesin (1): Rara. Oye mi, ṣugbọn fun awọn sise rẹ miiran ju ki won kan ma tele ilana ati ma se ikehu iyipo merindinlogun. O nse ọpọlọpọ awọn ohun miiran loojọ. Nibo lo tile gba ase to ba je pe eni na ko ngbe ninu tempili?

Prabhupāda: Ko ye mi. Guru ni alase. E ti gba be.

Bali Mardana: Fun gbogbo nkan.

Jayatīrtha: Ka so wipe, mo ni se ara mi, mo ngbe ni ita, sugbon emi o se ida-meji owo oya mi. Ti o ba je be iṣẹ ti mo ti n ṣe bayi, se iyen na gangan wa labe ase guru?

Prabhupāda: O daju pe eyin o tele itọsọna guru. Ododo pẹtẹlẹ oro niyen.

Jayatīrtha: Be lo je wipe gbogbo ise loojọ, nšišë, o tumo si pe mi o n tele awọn itọnisọna ti Oluko. Iṣẹ-ṣiṣe laigba ašẹ.

Prabhupāda: Bee ni. Ti o ko ba tẹle awọn ẹkọ ti Oluko, o ti wa ni ṣubu lẹsẹkẹsẹ. boseje niyen. Bibeko kilode ti e fi nkorin, yasya prasādād bhagavat-prasādo? Ojuse mi ni lati se itelorun oluko. Bibeko emi o sini ibi kankan. Nitorina ti o ba fẹ lati wa ni besi, ki o si ṣàìgbọràn bi o ba fẹ. Sugbon ti o ba fẹ lati wa ni dada ni ipo rẹ, o ni lati tẹle muna awọn ẹkọ ti oluko.

Olufokansin (1): A le ni oye gbogbo awọn ilana yin nipa kika awon iwe yin nikan.

Prabhupada: Beeni. Lonakona, tẹle awọn ilana. O se pataki. Tẹle awọn ilana. Nibikibi ti o ba wa, ko se pataki. O ti wa ni aabo. Tẹle awọn ilana. O si wa ni aabo nibikibi. Ko ṣe pataki. Gege bi mo ti wi fun yin pe, mo ti ri Oluko Mahārāja mi ko si waju ọjọ mẹwa ninu aye mi, sugbon mo tọ ẹkọ rẹ. Mo je baale (grhastha) nigba na, emi o si gbe pelu won ninu Maṭha, ninu tempili. O ti wa ni wulo. Opolopo awon arakurin ni se niyanju wipe " O yẹ ki o wa ni akoso tẹmpili Bombay yi, yi, pe, ti ..."" Guru Mahārāja sowipe," Bẹẹni, o dara ki o gbe ni ita. Iyen dara, yi o si ṣe ohun ti o wa ni nilo bi ojo ba se nlo.

Elesin: Jaya! Haribol!

Prabhupāda: Bee lo se wi. Ko ye mi ni akoko ohun ti o nreti. Dajudaju, Emi mọ pe, o fe ki nse iwàásù.

Yaśodānandana: Mo ro pe e ti ṣe eyi ni sayin ara.

OLufokansin: Prabhupāda! Haribol!

Prabhupāda: Bẹẹni, ṣe sayin ara nitori emi tẹle muna awọn ẹkọ ti Oluko Mahārāja mi. O pari. Bibeko emi o l'agbara temi. Emi o pa idan ki dan? Se mo se? Abi a nse wúrà lojiji? (erin) Sibe sibe, moni awon omo eleyin to dara ju awon guru ti won nṣe wura ojiji.