YO/Prabhupada 0146 - Teba se gbigbasilẹ oro na ti mio ba sinbi mo, gege bi mo sen soro ni rekoodu ma ri teba tun gbo



Lecture on BG 7.4 -- Nairobi, October 31, 1975

Kṛṣṇa si sowipe kilode teyin sen ronu nipa awon nkan aye yi. Awon oni sayensi femo nipa ile-aye yi. kilon pe wan gan? Awon ton monipa ile. Wan keko nipa ile: Nibo ni wura wa, nibo ni eedu wa? nibo ni eleyi tabi toun wa?" orisirisi nkan lon femo nipa, sugbon lati bo lonti wa, awon eyan yi o mo. Nibi Kṛṣṇa ti salaaye wipe bhinnā me prakṛti: Agbara mi leleyi." Bawo ni awon kemika ati awon nkan ile yi tiwa, gbogbo eyan lofe mo. Idaaun na wan bi. Idaaun na leleyi,

bhūmir āpo 'nalo vāyuḥ
khaṁ mano buddhir eva ca
ahaṅkāra itīyaṁ me
bhinnā prakṛtir aṣṭadhā
(BG 7.4)

Bhinnā prakṛtir aṣṭadhā. gege bi mon sen soro, teba se gbigbasilẹ oro na ti mio ba sinbi mo, gege bi mo sen soro ni rekoodu ma ri teba tun gbo. Agbara mi niyen, sugbon bhinnā, oyato simi. Egbudo ni oye nipa oro yi. Lati agbara Olorun, Krsna ni gbogbo nkan ti wa, sugbon itumo ile-aye yi niwipe, Krsna ti sonu laye wa. Nibo ni agbara yi tiwa? Eto to sonu niyen. Bhinnā, gege bi apeere timo fun yin. Teba tun rekoodu mi gbo, eniti mo nipa re kosi bosele mo eni to loun na. Sugbon eni toba mo le sowipe "Ohun Prabhupada tabi Swamiji niyen." gege na, agbara si wa nbe, sugbon nitoripe ati gbagbe orisun agbara yi tabi nitoripe awa o mo orisun agbara yi, nitorina lasen gba awon nkan aye yi bi ipinnu gbogbo nkan. aimokan wa niyen.

Awon nkan to wa ninu prakṛti yi, tabi ile-aye yi: bhūmir āpo 'nalo vāyuḥ khaṁ mano buddhir eva ca (BG 7.4). Nibo ni gbogbo eleyi tiwa? Krsna salaaye wipe " Agbara mi ni gbogbo e". Nitoripe agbudo mo, taba feni oye nipa Krsna agbudo monipa ile-aye yi, kini tumo omi yi, kini itumo ina yi, kini itumo afefe, kini itumo okan wa, kini itumo ara-eda. Awon nkan aye yi agbudo mo nibo lonti wa. awon eyan ma sowipe lati akojopo awon kemika hydrogen ati oxygen ni omi ti wa. Sugbon nibo ni awon kemika yi, hydrogen, oxygen ti wa? Wan o le daaun. nitorina wan pe ni acintya-śakti. Acintya-śakti. teba ko lati gba acintya-śakti, ninu Olorunn ni acintya-śakti wa, agbara tiole yewa, teba tisegbe kan, iyen wipe ko s'Olorun niyen. Acintya-śakti-sampannaḥ


Nisin eyin na ti ni oye nipa acintya-śakti gbogo wa lani acintya-śakti nitoripe nkankana laje pelu Olorun. Iwonba kekere la je. iwonba melo? śāstra ti salaaye iwonba na.. Keśāgra-śata-bhāgasya śatadhā kalpitasya ca jīva-bhāgaḥ sa vijñeyaḥ sa cānantyāya kalpate (CC Madhya 19.140). Keśāgra-śata-bhāgasya. seyin le so. iwonba melo? teba mu irun ori ke pin s'ona ogorun. kesi mu ikan ninu awon ogorun na kesin pin s'ona ogorun si Itumo yen niwpe eyokan ninu egberun. ìfẹ̀sí ààyè jiva niyen. keśāgra-śata-bhāgasya śatadhā kalpitasya ca jīva-bhāgaḥ sa vijñeyaḥ sa cānantyāya kalpate (CC Madhya 19.140).

Awon nkan aye yi nikan ni oju wa leeeri, awon nkan to koja nkan aye yi, awa oni oye nipa re. sugbon lati śāstra agbudo gbo lati śruti. Nigbana lemani oye. ese-iwekan wa ninu Bhagavad-gītā, indriyāṇi parāṇy āhur indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ manasas tu parā buddhiḥ (BG 3.42). nibi wansi sowipe mano buddhiḥ. Manasas ca parā buddhiḥ. Ogbon wa si gaju okan wa lo. Nibomi wansi salaaye wipe nkan aye yi ni iye-ara wa Indriyāṇi parāṇy āhuḥ. Nkan afoju wo. Tin ba ri Okurin, itumo re niwipe mole ri ara re, oju re, eti re owo re ati ese re. Nkan afoo ju wo niyen. sugbon lori gbogbo eleyi ni okan wa toni idari lori iye-ara wa. Kosi besel ri yen. Indriyāṇi parāṇy āhur indriyebhyaḥ paraṁ manaḥ (BG 3.42). Ogbon wa sini idari lori Okan wa. Manasas ca parā buddhiḥ. Egbudo keko bayi. sugbon teba sowipe " ko s'Olorun" bi awon eyan loju titi, iranu niyen. Ema gbe ile-aye yin bi awon asiwere. Egba oro Bhagavad-gītā. Esi ko nipa gbogbo nkan, Esin yi wan sisi fun gbogbo eyan.