YO/Prabhupada 0156 - Mon gbiyanju lati ko awon eyan ni nkan ton ti gbagbe



Arrival Address -- London, September 11, 1969

Onirohin: Ejo Sa, kilehin ko awon eyan?

Prabhupāda: mon gbiyanju lati ko awon eyan ni nkan ton ti gbagbe.

Elesin: Haribol! Hare Kṛṣṇa! (Erin)

Onirohin: Kini ye je?

Prabhupāda: Eto Olorun. Awonmi ninu yin sowipe ko s'Olorun mo, awonmi ninu yin sowipe Olorun ti ku, Awonmi tun sowipe ofurufu l'Olorun je. Iranu ni gbogbo eleyi. Mofe ko gbogbo awon eyan wanyi pe Olorun wa. Ise mi niyen. Awon oniranu lewa bami, mafi han wan pe Olorun wa. Egbe imoye Krsna mi niyen. Ipenija loje fun awon alainigbagbo eyan. Olorun n'be. Bawa se joko sibi ele ri Olorun oju s'oju. Teba je olooto ati teba mu ise yi ni pataki, o lese se. sugbon nkan to saanu niwipe afe gbagbe Olorun; nitorina lasen faramo awon isoro aye yi. Gege na iwaasu ti monse niwipe edakun egba imoye Krsna yi s'okan kebale ni idunnu. Ema jeki awon iranu aye yi, maya, tabi itanra eni, tanyin je Ibeere mi niyen.

Elesin: Haribol!