YO/Prabhupada 0171 - E ma reti ijoba to da fun aimoye odun, afi...



Lecture on SB 1.2.28-29 -- Vrndavana, November 8, 1972

Gege bi varṇāśrama, wan gbudo keko. awon ipo okurin toyato gbudo keko lati di brāhmaṇa to daju. awon imi ma keko lati di ksatriya to daju. awon imi a di vaisya. koni si iwulo fun awon sudra... nitoripe sudra ni gbogbo eyan je. Janmanā jāyate śūdraḥ. lati ibimo, sudra nui gbogbo wa. Saṁskārād bhaved dvijaḥ. Sugbon lati di vaisya, tabi ksatriya tabi brahmana agbudo keko. Nibo ni eko yi wa? sudra nigbogbo wan. bawo lesefe ki ijoba awon sudra lori? awon sudra ti fi etan gba idibo. wande ti joko sinu ijoba. Nitorina ise soso tanni.... ni asiko tawayi, Kali, mlecchā rājanya-rūpiṇaḥ, jijeun, ati oti mimu, jije eran, oti mimu. Mlecchas, yavanas, wan ti wole sinu ijoba. Bawo lesefe ki nkan to da jade latinu ijoba yi? Egbagbe ijoba to da fun aimoye odun, afi teba da varnasrama-dharma yi. Kole sejo ijiba to da. Wan gbudo ni ksatriya to daju lati toju ijoba. gege bi Parīkṣit Mahārāja. Ninu irin ajo tonse, osi ri okurin dudu kan to fe pa maalu, lesekese lo mu ada jade: " Taloje, iwo asiwere yi?" ksatriya niyen. Awon vaisya lon tonju awon maalu. Kṛṣi-go-rakṣya-vāṇijyaṁ vaiśya-karma svabhāva-jam (BG 18.44). Gbogbo nkan lowa n'be. Nibo ni asa wan wa?

Nitorina ni egbe imoye Krsna yi seje nkan pataki. Awon olori awujo wa, wan gbudo mu eto yi ni pataki bawo lesefe soro nipa eto oro-aje ile aye yi. Ibi nikan ko, ibikibi. Aimokan ati itanra eni lon lo nibikibi. Ko daju. Sugbon nibi o daju: vāsudeva-parā vedāḥ. Veda, eyin fun a won eyan l'eko, sugbon s'eyin le ko wan nipa Vasudeva, nipa Krsna? wanti so Bhagavad-gītā d'eewọ. Vasudeva n'soro nipa ara re, sugbon eewo loje. sugbon tenikan ban kawe, ton ka iranu, koni soro nipa Vasudeva. Otan. Bhagavad-gītā tioni Kṛṣṇa. Nkan ton sele niyen. Iranu lasan. Bawo lesefe ri awujo awon eyan to daju ninu awujo iranu. Ipinnu aye yi leleyi: vāsudeva-parā vedā vāsudeva-parā makhāḥ, vāsudeva-parā yogāḥ. Awon yogi to po gan wa, ton se yoga laisi Vasudeva - ton fika temu. Otan. Yoga ko leleyi.