YO/Prabhupada 0182 - Teba de ti fo ara yin tan, E toju re bee



Lecture on SB 2.3.15 -- Los Angeles, June 1, 1972

Eree to wa ninu pe awan gbo nipa Krsna nigbogbo igba niwipe, gbobo ese wa ma tan. Afi tawa ba lese kosejo pe awa sinu ile-aye yi. Gege na agbudo pari gbogbo ese wa taba fe pada losi ile Olorun. Nitoripe Ijoba olorun wa ni mimo Kos'eda kankan toje elese tole wonu ibe. Gege na gbogbo wa gbudo yasi mimo. Bhagavad-gita na ti so be. Yesam anta-gatam papam. " Eyan le fi ipaari si gbogbo ese to wa ninu aye re," yesam tv anta-gatam papam jananam punya-karmanam, " kosi foju awan ise to daara, lai se mo.." Egbe imoye Krsna wa lati fun awon eyan l'aye lati fi ipaari si gbogbo ese ewan. kosi fi ara re ni toto: lai ni imo ako ati abo, lai moti, lai jeran, lai ta tete. Taba le tele awon ofin wanyi, lehin ipilẹṣẹ mi, gbogbo awon ese ma tan. tima si fi ara mi ninu ipo toje wipe , tin mio le tun bosinu ese? sugbon teba ti fo ara yin tan, ketun mu iyepe ke da s'ara - iru ilana bayi o le ranyi lowo. teba sowipe, " Mole da idoti sara", kini iwulo pe eyin fo ara yin?

E fo ara yin. Teba de ti fo tan, e toju e be. Nkan ta fe niyen. gege na o lese se teba ni asepo pelu Krsna lati awon teba gbo nipa re. Otan Egbudo gbiyanju lati wa ni mimo nigbogbo igba. punya-sravana-kirtanah niyen. Teba gbo nipa Krsna, lehin na punya, ema wa ninu ipo to wa ni mimo nigbogbo igba. Punya-sravana-kirtanah. Ke korin tabi... Nitorina awa ti fun yin ni ilana ke korin Hare Krsna, Hare Krsna, Krsna Krsna, Hare Hare/ Hare Rama, Hare Rama, Rama Rama, Hare Hare. Gege na agbudo gbiyanju ka ma wo luleni ese. gbogbo wa gbudo se jeje, ka si fi ara wa ninu ilana orin kiko yi. Lehin na gbogbo nkan ma da. gege na srnvatam sva-kathah krsnah punya-sravana-kirtanah (SB 1.2.17). teba gbo nipa Krsna die die, gbogbo nkan idoti ninu okan yin ma ya si mimo.

Awon nkan idoti niwipe " Ara mi nimoje; Omo-ilu America nimi; omo-ilu India nimi; Hindu nimi; Nkan bayi bayi nimi; Orisirisi idaabo ni emi wa ni. Sugbon emi tio ni idaabo kankan mowipe " Iranse Olorun tayeraye nimi." Otan. Eyan o ni idanimọ kankan. mukti niyen. Nigba teyan ba wa sori oye wipe " Iranse ayeraye Krsna, Olorun nimi, ise kan soso timoni ni lati sise fun," mukti niyen. Itumo mukti ko niwipe ema ni owo meji si tabi ese meji si. Rara. Nkankanna loje, ema ya si mimo. Gege bi Okurin toni iba. Awon aami aisan yi si po gan, sugbon lesekese ti iba yi ba tan, gbogbo awon aami yi ma lo. Iba tani ninu aye yi niwipe, a feran igbadun. Igbadun. Iba ta ni leleyi. tabi bere sini sise ninu imoye Krsna, gbogbo ejo igbadun yi gbudo tan. Iyato to wa niwipe. Idanwo to wa niyen pe eti ni ilosiwaju ninu imoye Krsna.