YO/Prabhupada 0185 - Awa o de gbodo jeki awon asepo ile-aye yi bawa ninu je



Lecture on SB 3.26.35-36 -- Bombay, January 12, 1975

Ema daduro sinu awon eto wanyi. Awon eto wanyi wulo tebale ni ilosiwaju ninu eto imokan nipa Olorun. Sugbon etba kan tele awon eto wanyi lai ni ilosiwaju ninu eto imokan Olorun, lehin na gege bi Śrīmad-Bhāgavatam se so tabi gege bi awonn Veda se salaaye, ise ife loje. Koni wulo. Nitorina ni Bhagavata se sowipe, " Esin ipo kini leleyi je." Kosi nkankan to baje teba pe ni Hindu tabi Musulman tabi Kristiani tabi Buddha. " Esin toba le jeke ni ilosiwaju ninu imokan nipa Adhokṣaja, esin towa lori ipo to gaju niyen. Adhokṣaja, oruko imi fun Krsna. Itumo Adhokṣaja ni awon eto ti awa o le mo nipa pelu irori lasan tabi pel'ejo riro, tabi awon imoye aye yi. Nkan ton pe ni Adhokṣaja niyen. Adhah-kṛtaṁ akṣajam jñānaṁ yatra. Agbudo sumon Adhokṣaja. Orisirisi ipo imoye lowa: pratyakṣa, parokṣa, aparokṣa, adhokṣaja, aprākṛta. Sugbon agbudo tele aprakrta, towa lor ile-aye yi. Adhoksaja summon awon imoye to kere gan, pratyakṣa, parokṣāparokṣa. Awon eyan tonwa lori ipo kaniṣṭha-adhikāra.

arcāyām eva haraye
pūjāṁ yaḥ śraddhayehate
na tad-bhakteṣu cānyeṣu
sa bhaktaḥ prākṛtaḥ smṛtaḥ
(SB 11.2.47)

Gege na ipo prakrta ni imoye pratyaksa, iwoye to daju, ati imoye lati parampara. Pratyakṣa, parokṣa, lehin na aparokṣa, imokan nipa era eni, lehin na adhokṣaja, aprākṛta. gege na imoye aprakrta ni imoye Krsna. Ipo to gaju nipa imoye Krsna loje, imoye aprakrta. gege a taba de ipo adhoksaja, awon ofin. Agbudo tele awon ofin wanyi dada. Imoye aprakrta wa fun awon paramahamsa. Nkan ton pe ni raga-bhakti. Awon ipo bi, pratyaksa, paroksa, viddhi-bhakti lon je. sugbon laisi viddhi-bhakti, kosi basele de ipo raga-bhakti, botilijepe ipinnu wa niyen. Rāgānugā, Lati se rāga-bhakti agbudo tele ilana awon elesin ni Vrndavana. Nkan ton pe ni raga-bhakti niyen. Awon alabasepo Krsna. Konsepe ama di alabasepo tinmotinmo ti Krsna, sugbon taba tele ilana ti awon elesin tayeraye re ti funwa, awa na le gonke si ipo raga-bhakti. Nkan ton pe ni para-bhakti niyen. dandan nipe kani para-bhakti.

brahma-bhūtaḥ prasannātmā
na śocati na kāṅkṣati
samaḥ sarveṣu bhūteṣu
mad-bhaktiṁ labhate parām
(BG 18.54)

Gege na egbe imoye Krsna yi ti dagba diedie sori ipo raga-bhakti ati para-bhakti. Lehin na Ile aye wa ma ni ilosiwaju. awa o de gbodo jeki awon asepo ile-aye yi bawa ninu je. bi wanse so nibi, mṛdutvaṁ kaṭhinatvaṁ ca śaityam uṣṇatvam eva ca. Awon nkan yi ma funwa ni idamu. kasowipe awa sun si ilele. kaṭhinatvam loje: o le gan. Sugbon tawa bani aga timutimu, mrdutvam niyen. gege na, śītoṣṇa. Omi, nigbami a tutu, nigbami a gbona gan. nkankanna loje pel'omi, ti oju ojo ba yipo, oun na si yipo tele. awọ-ara wa ni orisun gbogbo irora ati igbadun. Gege na tawa ba mowipe " Ara mi ko nimoje", agbudo ni imokan ara-eni , ātmānubhūti.

Taba sen dagba si ninu imoye awon eto mimi, beena lama wole sinu ātma-stha. nkan tob pe ni sthita-prajna niyen. Lehin awa o le ni inira mo. Agbudo se ikeko lati ma jeki awon inira yi bawa ninu je. Agbudo se bayi. Nitoripe ara wa ko laje, emi ni wa, ahaṁ brahmāsmi, Mi o wa pelu awon eto ile-aye yi, sugbon oti bami lara mu, gege na pelu ikeko mo gbudo wa sori ipo emi. Taba de tin se ikeko na, agbudo faramo awon nkan. Nkan tonpe ni bhajana, sadhana tabi tapasya, ifaramo. Awon nkan tojepe ayato si subon ati bere sini se idanimo pelu wan, lehin na agbudo gbiyanu lati wa sori ipo ifaramo ton pe ni tapasya. Itumo tapasya niyen. Inira nitumo Tapah, gbe a faramo awon inira.