YO/Prabhupada 0191 - Wanle ni idari lori Krishna - Bi Vrndavan se ri niyen



Lecture on SB 6.1.52 -- Detroit, August 5, 1975

Prabhupada: Pelu Ore-ofe Krsna, ati ore-ofe guru, awon mejeji.. Ema gbiyanju lati gba ore-ofe ikan soso. Guru kṛṣṇa kṛpāya pāya bhakti-latā-bīja. Pelu ore-ofe guru eyan le ri Krsna. kṛṣṇa sei tomāra, kṛṣṇa dite pāro. Lati sumon guru itumo re ni wipe agbudo bere Krsna lowo re. Kṛṣṇa sei tomāra. Nitoripe Krsna l'oga, sugbon taloni idari lori Krsna? Awon elesin re. Krsna ni Oludari, sugbon awon elesin re ni idari lori re. Krsna niyen, bhakta-vatsala. gege bi baba wa, tabi adajo giga Oni iroyin kan wipe, eni wa ri Gladstone toje alakoso ijọba ni ile aṣofin Sugbon Gladstone sofun " Duro demi, oni nkan timon se." Gege na osi joko sibe fun wakati to po, lehin ara bere sinifun: " Kini okurin yi n'se? Gege na osi fe lowo nkan ton se... Adajo n'sere bi esin omore si gun l'eyin. Ise ton se. Se ti ri bayi? alakoso ijọba ni ile aṣofin yi ni idari lori gbogbo ijoba awon geesi, sugbon omo re sin wa bi esin nitori ife toni fun. Nkan ton pe ni'fe niyen.

Gege na Krsna ni Oludari to gaju.

īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ
sac-cid-ānanda-vigrahaḥ
anādir ādir govindaḥ
sarva-kāraṇa-kāraṇam
(Bs. 5.1)

Oun ni Oludari to gaju, sugbon awon elesin re ni idari lori re, Śrīmatī Rādhārāṇī. Wan ni idari lori e. Lati monipa awon nkan ton sele laarin... Sugbon Krsna fe ki awon elesin re ni idari lori re. Iseda Krsna niyen. Gege bi mama Yasoda. Iya Yasoda ni idari lori Krsna, ton fokunso: " alaigbọran ni e, ma fokun so e mole." Iya Yasoda ti yo egba jade, Krsna si bere sini sukun. Gbogbo awon nkan wanyi lema ka ninu Śrīmad-Bhāgavatam, Adura Kunti, ton dupe lowo Krsna pe "Krsna tayataya mi, iwo nmi eda to gaju. Sugbon to ba to ri egba Iya Yasoda wa bere sini sunkun, mo fe ri bi eleyi se sele." Gege na bhakta-vatsala ni Krsna je, to je wipe Oludari gbogbo nkan loje. Sugbon awon elesin bi Iya Yasoda, awon elesin bi Radharani, elesin bi awon gopi, elesin bi awon oluso maalu, wanle ni idari lori Krsna. Bi Vrndavan se ri niyen.

Gege na egbe imoye Krsna yi femu yin losi be. Awon ode yi tii yipo lori ona. Wan o mo nipa iye egbe imoye Krsna. Wanfe fun agbaye ni ipo to gaju Awon eleyi o fe di nkankanna pelu Olorun sugon wanfe funyin ni idari lorui Olorun. Egbe imoye Krsna wa leleyi.

Ese pupo.

Elesin: Jaya!