YO/Prabhupada 0213 - Efi ipaari si iku - Lehin na mole ri agbara idan teni



Morning Walk -- June 17, 1976, Toronto

Bhakta Gene: Mo ni ibeere kan lokan mi. Ninu Ẹsin igbagbọ won ni itan-akọọlẹ to han awon eyan pelu agabra O si ni awon alagbara to gbajumọ, sugbon imi ninu won o si gbajumọ bawo ni eyin ma se iyasoto ninu awon alagbara wonyi.

Prabhupāda: Pe eyan ni agbara idan iyen o so wi pe O aye re ya si mimo Awon eyan feran awon agbara idan bayi pely agbara idan ton ni won le se iyanu fun awon eyan. Otan. Sugbon eleyi o so wi pe aye won ti di mimo.

Bhakta Gene: Boya nkan ti mo so oye yin, mon soro awon alagbara to ni ifarafun Oluwa gege bi Àpọ́sítélì John ati Francis.

Prabhupāda: Ti eyan ba ni ifarafun ise Oluwa, kini iwulo agbara idan. Olorun ni Olugbala mi, iranse re ni mo je. Ki ni iwulo agbara asiwere wonyi?

Bhakta Gene: O da bi wi pe ọrọ ton pe ni agbara, awon eyan sin lo ni ilokulo ni Orile-ede wa.

Prabhupāda: Ko si nkan to kan wa pelu awon eyan Ti iwo be je iranse Oluwa, Olorun wa. Ise re ni ko ji'se. Otan Ki lode te fe agabra idan? lati le se iyanu fun awon eyan otan E sin Olorun. Otan. O si rorun. Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Ibo ni ibeere agbara idan. Ko soro Oluwa so wipe " e si ronu mi, ke yin mi logo, ke si gbadura si mi". Otan Ki ni iwulo agbar idan?

Arakurin Indiana: Mo ro pe...

Prabhupāda: Ele ro nkan te ba fe.

Arakurin Indiana: Rara sa. Oni ibẹrẹ oyun ti o bo si...

Prabhupāda: Ironu yin O ni itumo afi teba rori wo.

Arakurin Indiana: Rara sa. awon eyan so wi pe agabra yi ati itesiwaju ninu ise Olorun lo ti wa O da bi wi pe nkan to fe so niye.

Prabhupāda: Isoro aye yi ni wi pe awon eyan sin ji ya opin wa ni lati le pada si ijoba Orun Awon eyan O si mo. Won fi agabra fi se iyanu fun awon eyan. Kon si fi ipaari si iku, nigbana mo le gba pe alagbara ni yin Iru agbara asiwere wo leleyi? Se le fi ipaari si iku? se le se? Ki wa ni itumo agbara. Iranu Isoro to wa ni wi pe, mo si ni ara eda mo de sin ji ya Nitoripe lesekese ti eyan ba ti ni ara eda eyan yi, o ma bere si ni ji ya lehin ti mo ba ti tun da aye mi, ma si ku Tathā dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). Akori mi tun bere ni ye Gege na lati aye to si kere ju tit lo si awon anjeli, gbogbo wa ku asi tun pada wa Isoro ti emi ni le leyi. Kini Agbara idan ma se ninu gbogbo eyi? Awo o si mo isoro to wa. Iwe mimo Bhagavad-gītā ti fi ye wa Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Isoro te ni le leyi. Pe a ma wa si aye gege na iku a si mu yin lo Isoro aye o le tan teba si wa laaye Jarā-vyādhi. Nipataki Ajo arugbo ati aarun, isoro to le gan ni won je. Iru agbara wo lo le fun yin ni iranlowo? Se agabra yin le fi ipaari si ibimo, aarun, ka ma d'arugbo, ati iku? Ti agabra yin o ba ka, ko ni iwulo Eyin o mo nkan ti opin aye je, eyin o si mo awon isoro aye. won se iyanu kekere pelu agabra die to ni awon eyan de ma saa tele won " Ewo Alagbara"

Arakurin Indiana: Ki ni anfaani asepo pelu awon elesin?

Prabhupāda: Beeni. Satāṁ prasaṅgān mama vīrya-saṁvido bhavanti hṛt-karṇa-rasāyanāḥ kathāḥ (SB 3.25.25). Nitorina awa si fe sādhu-saṅga Asepo pelu awon elesin. Nkan ta fe leleyi. Aye wa asi ni aseyori. Awa o fe agbara idan.