YO/Prabhupada 0224 - E ma ko ile giga lori ipile tio da



Arrival Address -- Mauritius, October 1, 1975

ìmòye oun se nkan afori ro sayensi ti gbogbo sayensi iyoku ti jade ni ìmòye je. gege na egbe wa sin gbiyanju lati ko awon eyan lori sayensi to ju gbogbo sayensi lo. Ni alakoko, " Ta ni yin" Se ara eyan yin le je, tabi se eyato si ara yin? Eleyi se pataki sugbon ti e ban ko ile giga lori ipilẹ ti o da, ile na o ni duro. ewu ma wa nibe Gege na ilaju aye isin na ti beere loori ipilẹ ti o da. Awon eyan so wipe ara wan ni wan je Omo India ni mi, Omo America ni mi, Esin Hindu ni mon se, tabi ti Onigbagbo awon afaani ara ni gbogbo eyi je Nitoripe mo ti gba ara yi lati baba ati iya to je Onigbagbo, nitorina Onigbagbo ni mi. Sugbon mo yato si ara mi Nitoripe mo ti gba ara lati Baba ati iya Hindu, nitorina Hindu ni mi. Sugbon mo yato si ara mi gege na fun oye mimo, ofin ibẹrẹ ni eyi je pe " mo ya to si ara mi. Emi ni mi" ahaṁ brahmāsmi. ilana Veda ni eyi je. E gbiyanju lati mo pe emi le je, eyin o kin se ara yin Eto yoga wa fun oye oro yi Yoga indriya saṁyamaḥ. taba le ṣakoso fun iye-ara, nipataki okan wa... Okan ni olori gbogbo iye-ara wa Manaḥ-ṣaṣṭhānīndriyāṇi prakṛti-sthāni karṣati (BG 15.7). awan si ja fun iwalaye wa pelu okan wa ati iye-ara sugbon a si ro pe ara wa la je gege na taba fọkansi ale sakoso iye-ara wa.. die die aye wa Dhyānāvasthita-tad-gatena manasā paśyanti yaṁ yoginaḥ (SB 12.13.1). awon alagbara man gbokan le Olorun, Visnu. pelu ilana yi wan si da ara wan mo ise wa ni lati mo eni ta je. gege ibere eto yi ni wi pe agbudo mo pe, "Emi ni mi" Ahaṁ brahmāsmi.

Ninu iwe mimo Bhagavad-gītā, wan si ti saalaye gbogbo e Ti awa ba si ka iwe mimo Bhagavad-gītā, loodo eyan to ni imo re gege na gbogob nkan lo ma ye wa pe " ara wa ko la je", lai si anfaani Ise mi yato si ise ara mi Mi o le ni ifokanbale ti mi o ba o pe Emi ni mo je ipile ti oda fun imo ti yen je gege na ti awa be ni itesiwaju die o ma ye wa pe, ahaṁ brahmāsmi: "Emi ni mi" Lehin na Ibo ni mo tiwa? Krsna(Oluwa) si ti saalaye gbogbo nkan ninu iwe mimo Bhagavad-gītā Oluwa so wi pe mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ: (BG 15.7) Gbogbo awan eda wanyi wan se nkankanna pelu mi gege bi ina to tobi pelu ina to kere, ina ni awon meejeji, sugbon ikan ju ikeji lo Loori eto amuye ikankanna la je pelu Oluwa gege na a le mo ni pa Oluwa ta ba le mo ara wa, sasaro imi ni yen Sugbon a ye wa ju ta ba ni oye pe, " gege na amuye kanna ni mo ni pelu Oluwa, sugbon, Oun lo tobi, emi de kere" Oye to dára niyen je Anu, vibhu; Brahman, Para-brahman; īśvara, parameśvara - Oye to dara ni ey je Nitoripe mo ni amuye kanna peluj Oluwa iyen o to lati so mi di Oluwa Ni iwe mimo Veda, o si wi pe nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). nitya ni wa, ainiopin, Oluwa na Osi ni opin Eda laje, Eda na ni Oluwa je Sugbon Olori-eda loun je, Ainiopin AIniopin si ni wa, sugbon kilode to je pe Olori ko ni wa/ Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kāmān. Gege bi a se niOlori ni aye yi, Oun ni Olori to ga ju Oun lon toju wa. Oun lon s'eto nkan ti gbogbo wa be fe A si le ri ni awon Erin to wa ni Orile-ede Africa ta lon fun wan lounje? Aimoye kokoro to wan ninu yara yin, ta lon fun wan lounje? Eko yo bahūnāṁ vidadhāti kaman. gege na ta ba le mo ara wa, at ni Oye ara wa ni yen.