YO/Prabhupada 0230 - Ninu awujo Veda, isasoto merin lowa ninu awujo eda



Lecture on BG 2.1-5 -- Germany, June 16, 1974

Eleyi ni ìtàkurọ̀sọ laarin Arjuna ati Krsna lori ile-ijagun Kuruksetra Eto ìtàkurọ̀sọ yi si ni wi pe, ... Arjuna ti ri pe ni ipagọ keji awon ara ebi re si wa ni be Krsna si so fun pe " Olukaluku gbodo se ise re laai ronu ere to ma pa tabi pipadanu Gege bi iwe Veda se so, awujo awon eyan ni iyasoto merin Awon ipajo wan yi nkankanna lon je ni gbogbo agbaye Gege ara wa se ri, a si lori, ati apa, ati ikun, ati ese gege na ninu awujo awon eda, agbudo ni awon ipajo ton se ise bi opolo awon eyan mi asi toju awujo na, awon eyan mi ma se eto ounje wan si toju awon maalu wan de ta nkan awon iyoku ti wan o le se ise bi opolo, tabi kan le toju awujo eyan na ti wan si le se eto ounje, awon eyan ba won pe wan ni sudra ara eyan gbudo ni opolo ati apa ẹka ile iṣẹ t'ikun tabi t'ese.

Gege na Arjuna si je ikan nin awon ton toju gbogob awujo eyan to de fe ja ninu ogun na sugbon Krsna si so fun " ogbudo ja, ise re ni yen" ko si da ki eyan ma pa awon eda, sugbon ti eyan ba ni ota ese ko lo je ti eyan ba pa Ota na gege na ipajo keji lori ile-ogun Kuruksetra awon lon di Ota si Ipajo ti'Arjuna Ibere iwe Bhagavad-gita ni yen Idi fun gbogbo eyi ni lati ko Arjuna ninkan to se pataki ni imo mimo.

Gege na itumo imoye awon nkan momi ni wi pe egbudo mo nkan ti emi je ti eyan o ba mo nkan ti emi je, ibo ni imoye mimo re wa? awon ti feran ara wan ju. nkan ti awan pe ni ife-aye ni yen sugbon ti e ba ni imoye awon nkan to ya si mimo, a le so sipe oun na ti di mimo Gege na Arjuna o si fe ja pelu awon eyan ni ipajo keji nitoripe o ni ebi laarin wan. gege na Arjuna ati Krsna si ni itàkurọ̀sọ yi laarin ara wan.Sugbon oro laarin awon Ore lo je Nitorina, Arjuna si ri pe Oro ton so bi Ore ko si le fun ni esi fun isoro to ni. Osi di akeko Krsna Arjuna so fun Krsna, śiṣyas te 'ham śādhi māṁ prapannam: (BG 2.7) Ore mi Krsna, Otipe ti awan sin soro bi ore, nisin mo fe akeko re Si gbamila pelu awon ilana. Kini mo le se? Nitorina, Igbati Arjuna soro bayi Krsna si so fun wipe: śrī-bhagavān uvāca. Ta lon ba Arjuna soro? Krsna lo si fun wa ni iwe mimo Bhagavad-gītā Itakuroso laarin Arjuna ati Krsna lo je. Sugbon Vyasadev si ko si inu iwe gege bi isisn taba soro tan wan si ko sinu iwe Nitorina ninu iwe yi, O si so wipe, bhagavān uvāca. Vyasadeva ni olukowe , sugbon ko si wi pe " Emi ni mo soro O so wi pe, bhagavān uvāca- Oluwa so wi pe.