YO/Prabhupada 0248 - Iyawo to koja ẹgbàájọ ni Krishna fe , pelu ija lo si se igbeyawo gbogbo won



Lecture on BG 2.6 -- London, August 6, 1973

Pradyumna: Awa o si mo eyi to daju, ka si ni isegun lori wan tabi kon ni isegun lori wa Awon omo Dhṛtarāṣṭra si duro ni siwaju wa ni oju-ija, taba de pa wan, ko ye ka gbe mo

Prabhupāda: Ipajo meeji wanyi ton je ọmọ ẹgbọn si ara wan Omo marun ni Mahārāja Pāṇḍu ni , Dhṛtarāṣṭra ni omo ogorun Ebi kanna ni wan je, wan si ni oye laarin ara wan pe ti awon eyan lati ita ba fe ba wan ja wan si jowopo awon ogorun-aarun sugbon ni isin wan ja laarin ara wan, apa kan ogorun,apa keji maarun Nitoripe ebi ksatriya lon je, sugbon wan gbudo se ise wan ninu igbe yawo wan gan, wan gbudo ja Laisi Ija, ko si igbeyawo kankan to le sele ni ebi ksatriya Iyawo krsna ko ja ẹgbàájọ sugbon gbogbo igba to gbe yawa, Ogbudo ja Ija dabi ere idaraya lo je fun wan awon ksatriya gege na kosi mo boya iru ija bayi ni lati sele

Owe kan wa ni ede Bengali khābo ki khābo nā yadi khāo tu pauṣe Ti eyan ba ni idamu boya, ti mi o de mo boya kin jeun tabi rara Nigbami ale ni idamu bayi, se in jeun tabi kin ma jeun? Nkan to dani ke ma jeun Sugbon teba fe jeun, e jeun ni Osu Ṑpe, Pauṣa. Kilode? ipa ọna oorun ni oju-ojo ni ilu Bengal sugbon ni igba otutu Eyan le jeun nitoripe, ounje na ma wo ara Ajo ale si gun gan, ounje yin le wora dada Gege na ti awa ba ni idamu, boya ka se nkan tabi ka ma se jābo ki jābo nā yadi jāo tu śauce Se kin lo tabi kin ma lo? E ma lo Sugbon to ba je ipe ti iseda, egbudo daaun Jābo ki jābo nā yadi jāu tu śauce, khābo ki khābo nā yadi khāo tu pauṣe. Ogbon ori ni eyi je gege naArjuna ti ni idamu, " Se kin Ja gun tabi rara?" Ibikibi ni eleyi wa, Ti awon eyan ba fe jagun, wan rori wo gege bi ogun agbaye keji, nigbati Hitler fe jagun.. gbogbo eyan mo pe Hitler ma gbẹsan, nitoripe ni Ogun t'alakoko wan o ni isegun Nitorina Hitler si bere sini s'eto fun ti keji Ore mi kan lati ilu Germany wa si Orile-ede India ni Odun 1933 O so fun wa pe " Ogun ma wa" Hitler s'eto ogun gan, kole soro aisi ogun Nigbana Mr. Chamberlain ni alakoso ijọba ni ile aṣofin O si lo ba Hitler lati fi Ipaari si Ogun na, sugbon Hiter o gba Gege na ninu Ija yi, Krsna Si giyanju lati fi ipaari si ogun na O sofun Duryodhana " awon aburo re ni awon eyan to feba ja wonyi" O si ti fi agidi gba ijoba wan Sugbon ksatriya ni wan je, wan gbudo ni ọna ijẹẹmu Fun awon aburo maarun na ni abule arun soso, ninu gbogbo agbaye si fun wan ni abule marun pere Rara, mi o ni fun wan ni ile kekere gan laisi Ogun Nitorina Ogun gbudo wa..