YO/Prabhupada 0264 - Maya na sise fun Krishna, sugbon ise alai-dupẹ loje



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: elesin Oluwa ni Māyā?

Prabhupāda: Māyā o ni idari lori awon elesin ton ti ya si mimo.

Tamāla Kṛṣṇa: Rara. Mofe mo boya elesin Oluwa ni Māyā je?

Prabhupāda: Beeni Awon Olopa se iranse ijoba ko lon je? Se nitoripe awon Olopo man fiya je awon eyan, iyen owipe wan ti kuro ni ipo iranse ijoba? Ise alai-dupẹ ni ise wan. Otan gege na Māyā na s'ise fun Krsna, ise alai-dupe nani. Ise ti Māyā ni lati fiyaje awon ton je alainigbagbo ni Oluwa. Otan kon sed pe Māyā ti kuro labe Krsna ninu iwe Caṇḍī, iwe Māyā,wan si sowipe "Vaiṣṇavī. Wan juwe Māyā, pe Vaiṣṇavī lo je. gege bi eyin sen pe awon elesin ton ti ya si mimo ni Vaisnava, wan si juwe Maya bi Vaisnavi.

Viṣṇujana: bawo lesen s'aalaye awon nkan bayi, tode rorun?

Prabhupāda: Nitoripe gbogbo imoye na rorun Oluwa lo gaju, ewo lo si kereji Ma sowipe Olorun loje. Masi sowipe Ko s'Olorun Olorun n'be , alagbara lo je. Sugbon iwo si kere. Kini ipo yin? Egbudo di iranse fun Krsna. Oto oro niyen Iwakuwa teni yen ni awan pe ni māyā. enikeni ton sowipe " Ko s'Olorun, Olorun ti ku. Olorun ni mo je, Olorun ni eyin na". gbogbo wan ti toribo maya. Piśācī pāile yena mati-cchanna haya. gege bi eyan to ni isoro pelu awon iwin, eyan na ama so isokuso Gbogbo awon eyan yi si ni isoro pelu maya, nitorina wan se sowipe " Olorun ti ku. Olorun nimo je. "kilode ten se wa Olorun kakiri? Olorun si wa loju titi" Oponu ni gbogbo wan je Agbudo fun wan ni iwosan pelu Orin Hare Krsna Ilana iwosan fun wan ni yen Eje kon gbo die die aisan wan ma tan Teba fe ji eni ton sun, oyeke pariwo oruko re si eti re gege na mantra lati fi ji awon eyan ninu ile-aye yi niyen Uttiṣṭha uttiṣṭhata jāgrata prāpya varān nibodhata. Iwe Veda sowipe " Eyin eyan e dide" Ema sun mo Esi ni ara eyan to da, esi lo dada eyo ara yin kuro ninu itẹ mọlẹ māyā " Ase iwe Veda niyen Awan se ise na Hare Kṛṣṇa, ekorin Hare Kṛṣṇa ..

Elesin: Hare Kṛṣṇa!

Prabhupāda: Kilode?

Jaya-gopāla: Se asiko toti koja, pelu asiko tawayi, ati ojo iwaju, se nkankanna.....

Prabhupāda: Beeni, eyitokoja, ti isin, ati tojo waju, .. nkankanna niwan je, pelu iyato.. awon oni sayeni si ti fun wa ni esi alamọdaju okurin Einstein ti fihan wa gege bi asiko tokoja fun eyin yato si ti Brahma Asiko isin fun eyin yato si ti kokoro gege na asiko tokoja, tabi isin, tabi ojo iwaju-- ayeraye ni akoko wa gege bi ara wa seji si ni asiko se niyi fun wa. ayeraye ni akoko wa bi era kekere Ni wakati merinlelogun, gbogbo aye era ti tosi iawju re pelu Sputnik lati Orile-ede Russia, wan si yipo gbogbo aye yi ni wakati kan.. Rara, nkan ti mofe so niwipe wan yipo ile-aye yi nigba medogbon Ni wakati kan, Sputink ri ojo ati ale medogbon ni awon ipo giga, asiko to koja ati tisin wan yato si ara wan gege na asiko isin, ati asiko tokoja, ati ojo iwaju, wan ni asepo pelu iru ara teni Ni otooro kosi asiko to koja, kosoro isin tabi ojo iwaju. Alainiopin ni gbogbo nkan je Alainiopin le je, nityo śāśvato 'yaṁ na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Eyin o le ku. Nitorina... Awon eyan o mope alainiopin ni moje Kini ise mi t'ayeraye? Kini aye mi ti o lopin? nkan aye yi lon jo wan loju. Omo Orile-ede America nimi, Omo Orile-ede India nimi, Otan Aimokan ni yen Eyan gbudo wa idi ise alainiopin pelu krsna Nigbana lema ni idunnu. Ese pupo.