YO/Prabhupada 0271 - Acyuta ni oruko Krishna. Kole sokale lati ipo to wa



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

Nkanna ni amuye wa, sugbon iye na yato nitoripe amuye kanna lani, asi ni awon iwa bi t'Olorun, Krsna na Krsna si ni ife fun eni ton fun ni idunnu, , Śrīmatī Rādhārāṇī. gege na nitoripe aje nkankan na pelu Krsna, awa si ni awon amuye yi svabhava ni eleyi je sugbon taba wa sinu aye Krsna oni nkankan se pelu aye yi Nitorina, Acyuta ni oruko Krsna, Eni tio le sokale sugbon awon eyan le sokale.. Prakṛteḥ kriyamāṇāni. asi ti bosabe idari prakrti. Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ (BG 3.27). lesekese taba bosinu idimu prakrti, agbara ile-aye yi amuye meta ni prakrti ni, inu rere, ìjánu ati aimokan awa si ma mu kan ninu wan Nkan to sele niyen. kāraṇaṁ guṇa-sanga (BG 13.22). Itumo Guṇa-saṅga ni asepo pelu amuye to yato Guna-saṅga asya jīvasya, awon eda. Eyan le bere, " to ba je pe awon eda nkankanna lon je pelu Olorun, Kilode ti ikan ninu wan a di aja, ikeji adi orisa, Brahma? Karanam ni Idauunfun wan. guṇa-saṅga asya. ni idi gbogbo eleyi Asya jīvasya guṇa-saṅga. nitoripe eyan na ni asepo pelu guna Sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa.

Wan si ti juwe awon nkan yi ninu Upanisad, bi awon guna sen s'ise gege bi ina. Ina kekere si wa awon ina kekere na sile kuru ninu ina to tobi Nkan meta lole sele si awon ina kekere to jade lati ina to tobi ton ba subu lori ewe togbe, wan le gbina Ton ba subu lori ewe lasan, wan gbina die wa si ku Tonba si subu lori omi, lesekese lon ma ku awon ton wa labe idimu sattva-guna, wan logbon Wan l'ogbon. gege bi awon brahmana. Awon ton si wa labe idimu rajo-guna, awon lon feran awon nkan ile-aye yi awon ton wa labe idimu tamu-guna, wan yoole, wan de feran orun. Otan Awon amuye towa niyen. Itumo Tamo-guna ni wipe wan yoole wan de feran orun Itumo rajo-guna ni wipe wan feran ise sugbon bi ọ̀bọ Awon ọ̀bọ feran ati lo kakiri, sugbon wan o fibe da na. awon ọ̀bọ o le joko sibi kan.. wan gbudo ma fo kiri