YO/Prabhupada 0287 - E ji soke iranti yin ,ife yin fun Krishna



Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Prabhupāda: se ni ibere?

Madhudviṣa: Prabhupāda? saale ka Śrīmad-Bhāgavatam toba jade tabi ka foju si Bhagavd -gita nikan? lehin ka si tesiwaju, tabi ka bere sini ka Śrīmad-Bhāgavatam?

Prabhupāda: Rara. e ka Bhagavad-gītā . isasoto ni mo fi se, sugbon ni ipo emi nkankanna ni gbogbo wa teba ka Bhagavad-gita, ema ri nkankana ninu Śrīmad-Bhāgavatam. kon sepe nitoripe eti bere sini ka Śrīmad-Bhāgavatam. koye ke ka Bhagavad-gita mo. Bee ko. E ka awon iwe yi, ke korin Hare Krsna e tele awon ofin wa ke si gbe ile-aye pelu idunnu Ise toni idunnu ni ise wa Ka korin, ka jo, ka je prasadam Krsna, ka se awon aworan to da, ka si ni imoye. se fe nkan si? (erin)

Jāhnavā: Bawo lase gbagbe Krsna ni ibere?

Prabhupāda: Hm?

Tamāla Kṛṣṇa: Bawo lase gbagbe ife wa fun Krsna ni ibere?

Jāhnavā: Rara. ife ko, Bawo lase gbagbe ife wa fun Krsna ni'bere?

Prabhupāda: imo nkan wa si wa. sugbon oye ke nife Krsna , nkan teti gbagbe niyen igbagbe je ikan ninu iwa adayeba tani nigbami a le gbagbe nkan, nitoripe asi kere gan nitorina nigbami mo le gbagbe nkan timo se ni ale ana gege igbagbe je ikan ninu iwa tani lehin na telomi bafe jeka ranti, iyen na si le fun wa gege na Krsna ni eni toye ka nife fun sugbon bibakon ati gbagbe Kowulo lati bere sini wadi nkan tati gbagbe. Ise tioni aseyori niyen Ati gbagbe, otooro niyen nisin egbiyanju lati ranti. Ema bere sini bere pe ijowo nimo gbagbe teba tie mo, kini iwulo.? fun apeere teba loba Ologun, kole bere sini bere pe, lati ibo ni aisan na tiwa, Ijo wo lo bere. rara Oma gbowo sori ara yin, asi wo pe al'aisan, ade funyin ni Ogun gege na gbogbo wan jiya. Koseni to le jiyan kilode te sen jiya? eti gbagbe Krsna. Otan Nisisn oye ke gbiyanju lati ranti Krsna, ema ni idunnu Otan. O rorun gan ema bere sini wa itan teti gbagbe Eti gbagbe, otooro niyen, nitorina lesen jiya asi ti mu ona Imoye Krsna wa lati ranti pe agbudo nife fun Krsna. Ekorin hare Krsna, e jo, e je ounje Krsna teeba mo iwe ka, efeti sile ke gbo nkan tan so gbogbo lani eti ati ahon ele korin Hare Krsna tabi ke gbo Bhagavad-gita tabi Śrīmad-Bhāgavatam lowo awon eyan ton ni oye na kosi isoro Kodesi ẹtọ idayatọ elo ounkooun teba ni. Otan Egnudo gbawipe," Oye kin gba imoye Krsna" Sugbon esi ni ominira lati se bo se wunyin teba si wipe " rara. kilode tefe kin gba imoye Krsna? koseni tole funyin pelu agidi sugbon teba gba, o rorun gan. E gba bee