YO/Prabhupada 0295 - Agbara kan soso lon s'eto gbogbo eda ninu aye yi



Lecture -- Seattle, October 4, 1968

Ile-aye yi tawa ni... ni awon ayemi tawa ati gbadun gan.. Kilafe gbadun ninu aye yi? Darmin si sowipe ki ayeyi to bere, Obo ni gbogbo wa Ni orile-ede India awa sini iriri pelu awon Obo gbogbo awon Obo to wanbe wa pelu obirin ogorun Iru igbadun wo lawa ni? gbogbo igba lon ni idaraya, gbogbo idaraya ton si ni, kosi aaya okurin kankan tioni to aaya obirin medogbon Awon elede na sini to mejila.. kodesi isasoto pe Mama mi leleyi, tabi aburo-obirin mi leleyi seti ri?wansi gbadun. seyin wa ro pe ile-aye eyan yeko ri bayi bi awon aja ati elede? se igbese aye yin ni lati fi gbadun? rara Otipe tatin gbadun Nisin? Vedanta sowipe , athāto brahma jijñāsā. Ati wadi Brahman ni ile-aye yi wa fun Kini Brahman? śvaraḥ paramaḥ brahma or parama, īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs. 5.1) Para-brahman ni Krsna je. sugbon Brahman sini gbogbo wa. Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs. 5.1). gege bi eyin se je Lati orile-ede America sugbon Olori ilu yi Johnson, oun ni omo-ilu to gaju Awon Veda si sowipe Olori gbogbo wa l'olorun Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Tal'Olorun? oun ni eda to gaju ni aye yi. Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān.

Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. itumo re ni wipe edan kan soso lon s'eto gbogbo eda ni aye yi gege bi awon ebi. Okurin ile loma seto awon nkan ti iyawo re ba fe, ati awon omo re. gege na ijoba yeko seto gbogbo nkan ti awon omo-ilu ba fe Sugbon kosi nkan to pe ninu aye yi Eyan le seto fun ebi re, fun awon awujo eyan, fun orile-ede re sugbon kosi besele s'eto fun gbogbo eyan Aimoye awon eda to wa. ta lon seto ounje wan? Talon fun awon era ni ounje? Talon fun wan? teba si lo si Odo, awon pepeye topo si wanbe talon toju wan? sugbon wansi wanbe aimoye eye, eranko, ati erin towa Erin sin ma jeun gan. talon fun lounge Ni odo tawa nikan ko, sugobn lori aimoyr isogbe-orun ni gbogbo eleyi tin sele Olorun niyen. Nityo nityānām Eko bahūnāṁ vidadhāti kāmān. gbogbo wa lasi wa labe itoju Olorun gbogbo nkan si pe.

pūrṇam idaṁ pūrṇam adaḥ
pūrṇāt pūrṇam udacyate
pūrṇasya pūrṇam ādāya
pūrṇam evāvaśiṣyate
(Iso Invocation)

Gbogbo isogbe orun si pe si ra wan Omi si wanbe ninu awon Okun ati Odo Orun a si la omi na Ni awon isogbe-orunmi , eleyi na sele omi na asi di ofurufu asi, asi ro kakiri gbogbo bi omi-ojo fun awon eso, ati igi.. gege na gbogbo nkan lo da agbudo ni oue eyan to da gbogbo nkan to dara wanyi Orun ran ni asiko toye, Osupa na sin jade ni asiko, awon akoko sin yipo lasiko Eri nipa Olorun si wa ninu Veda.