YO/Prabhupada 0297 - Enikeni toba femo nipa otito ayeraye - Ogbudo gba oluko



Lecture -- Seattle, October 4, 1968

Ninu ilana wa ādau gurvāśrayaṁ sad-dharma pṛcchāt. eyan gbudo gba oluko, osiye ko bi ni ibeere .gege na ninu Śrīmad-Bhāgavatam wan si sowipe jijñāsuḥ śreya uttamam. enikeni toba femo nipa Otito to gaju, ogbudo gba Oluko Tasmād guruṁ prapadyeta jijñāsuḥ śreya uttamam (SB 11.3.21) iwadi ni itumo Jijñāsuḥ. eyan tole waadi gege bi omode, bon sen dagbasi lon wadi itumo awon nkan lati obi re " baba ki leleyi, Mama ki leleyi?" oda bayi. Omode to feran lati wadi nkan, omo to logbon niyen agbudo kogbon ka si wadi awon nkna, Jijñāsa. Brahma-jijñāsā. lati wadi ni Olorun ni ile-aye yi wa fun Lehin ni aye wa le ni aseyori. Athāto brahma-jijñāsā. ti eyan bai beere tan , toti wadi awon nkan tan, kilowa ku? wan si so ninu Bhagavad-gītā: bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate (BG 7.19) lehin aimoye ibimo ninu ile-aye yi, lehin igbai eyan ba logbon, kiloma sele? Bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate: "Oma teriba funmi" Kṛṣṇa si sobayi. kilode? Vāsudevaḥ sarvam iti oti ni oye nipa Vasudeva, osi ti mowipe Kṛṣṇa ni Orisun gbogbo nkan Sa mahātmā su-durlabhaḥ. Iru eyan bayi le lati ri Caitanya-caritāmṛta sow ipe, sei bado catura: Ologbon ni eyan na je

Isọtunmọ eyan to logbon leleyi taba fe logbon agbudo bere sini seto base fe kogbon sugbon taba de logbon, kilole lati gba imoye Krsna yi? laise nkankan, ele gba.... Oluwa Caitanya ti muwa fun gbogbo wa kṛṣṇa-prema-pradāya te (CC Madhya 19.53). Osi ti fun wa ni ife Krsna. Rūpa Gosvāmī s'adura si Caitanya, namo mahā-vadānyāya kṛṣṇa-prema-pradāya te: " Oluwa mi Caitanya, koseni to ni inurere bi eyin". Kilode? Nitoripe eyin sin fun wa ni ife Krsna Ife Krsna tole lati ri lehin aimoye ibimo sinu ile-aye yi, eyin si fun wa. Egba lesekese Namo mahā-vadānyāya kṛṣṇa-prema-pradāya te kṛṣṇāya kṛṣṇa-caitanya. wansi mo pe Krsna leje Bibeko kolesese ki eleomi fun awon eyan nife krsna bayi Krsna leje esi lagbara na. Nigbati Krsna wa ko eto Bhagavad-gita ko si fun wa nife ara re O si sowipe sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). sugbon awon eyan o ni oye nkan ton so Nitorina Krsna si pada wa gege bi Elesin lati funwa ni ife krsna gege na nkan tawa sin bi gbogbo yin niwie ke gba imoye na sokan eyin na ma ri pe " Kosi nkankan ti mo fe " Mosi ni itelorun. Ese gan