YO/Prabhupada 0311 - We are Giving New Light - Meditation will fail. You take this



Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Omode: Um, Nigbati Oluwa Buddha wa, so joko nigbato n.sasaro.

Prabhupada: Beeni.

Omode: Mo rowipe ninu asiko tawayi eyan o le sasaro mo, sugbon Oluwa buddha, toje omo-Olorun osi sasaro.

Prabhupada: Beeni.

Omode: Sugbon asiko Kali na lowa?

Prabhupada: Beeni.

Omode: Se oto ni?

Prabhupada: Beeni.

Omode: Bawo lesele sasaro na?

Prabhupada: O da gan. (Erin) Nitorina awa daju Buddha lo. Awa sowipe kolese se mo taba fe sasaro. Se to ri bayi? Soye nisin? Oluwa Buddha sowipe, " E sasaro," sugbon awon elesin re o le se. Wan kuna. Awa sin salaaye dada, wipe kosi besele sasaro. Egba nkan tawan so. so ye ? Beeni. teyan ba so nkan fun e, to danwo tosi kuna, nitorina lawan sowipe " Ema se bayi. E gba nkan tawan so." gege bi wo se je omode nisin kosi bo sele sasaro, sugbon o le jo fun Olorun. Oluwa Buddha si mo pe awon eyan yi o le sasaro. Omo to logbon lo je. Sugbon lati fi ipari si gbogbo iranu ton se, O sowipe " E joko ke sasaro. Otan. (erin) gege bi omode ton fa ijogbon, Awon obi re ma sowipe, " Omo mi John, joko sibi." O mope kole joko, sugbon fun igba die asi joko na. Baba re gan mope kole joko, Sugbon fun igba die kosi dake die. Oda bayi. Ekorin Hare Krsna.