YO/Prabhupada 0325 - Try to Spread this KC Movement and this is your Sadhana



Class in Los Angeles -- Los Angeles, November 15, 1968

Imoye krsna yi da gan. Idanwo to wa niyen. enikeni le wa bere lowo awon omo-okurin wanyi bonsen lo pelu wan. Afi ton ba ni idunnu ninu eto emi, bawo lonsele fi gbogbo nkan bayi sile kon gba orin kiko Hare Krsna? Idanwo to wa niyen. Naiṣāṁ matis tāvad urukramāṅghrim. Matis tāvad. Matis tāvad urukramāṅghrim. Urukramāṅghrim. Urukrama, oruko imi fun Krsna niyen. Nkan to le gan nitumo Uru, ilana nitumo krama. Gege bi Krsna ninu Vāmana-avatāra, Osi rin tit de ofurufu. Urukrama ni oruko re je. Eyan o le gbokan le Krsna afi mahīyasāṁ pāda-rajo-'bhiṣekaṁ niṣkiñcanānāṁ na vṛṇīta yāvat. Kolese se t'aye na o ba wa lati fowokan ese eyan to je niskincana, tioni iyi fu awon nkan aye yi; mahiyasam, tosi ti fun aye re fun Krsn. Lesekese teyan ba pade iru eyan bayi, ole wa sori ipo imoye Krsna. Kos'ona imi. Naiṣāṁ matis tāvad urukramāṅghrim (SB 7.5.32). idanwo to wa ni wipe spṛśaty anarthāpagamo yad-arthaḥ mahīyasāṁ pādo-rajo-'bhiṣekaṁ niṣkiñcanānāṁ na vṛṇīta yāvat. danwo to wwa niyen, ona toye ka gba lati summon awon eyan patai niyen kasi gba imoye Krsna yi lowo re, pelu ore-ofe re. Lesekese teyan ba gba imoye yi, lesekese na ni igbala re ninu awon idimu aye yi ma bere. lesekese, lesekese. die die, to ban ti ni ilosiwaju, aye re a ma dunsi. Eyan le beere, teyan ba wonu egbe imoye Krsna yi lai rori wo, ti ko ba le paari na. Kini abajade to ma tele? Iyen na si wa ninu Śrīmad-Bhāgavatam. Tyaktvā sva-dharmaṁ caraṇāmbujaṁ harer (SB 1.5.17). Sva-dharmam.

Itumo Sva-dharma niwipe gbogbo wa ni ise to ye ka se. gbogbo wa. sugbon teyan ba fi ise to ye ko se sile, tyaktvā sva-dharmam.... gege bi awon omo-okurin at'obirin tonti wa sibi. gbogbo wan lon =i nkan ton se tele, sugbon wan si fi gbogbo e sile lati wa sinu egbe imoye Krsna yi. fun awon eyan bayi Bhagavata sowipe, tyaktvā sva-dharmam... Ise eyan nitumo Sva. Nisin esin kon ni dharma tan so. Ise apinfunni. Tyaktvā sva-dharmaṁ caraṇāmbujaṁ harer. Ka sowipe lehin igbato gbo awon or lati egbe imoye Krsna y losowipe " Nisin mofe bere imoye Krsna yi," to si fi gbogbo ise re sile Tyaktvā sva-dharmaṁ caraṇāmbujaṁ harer bhajann apakvo 'tha patet tato yadi (SB 1.5.17). Bhajann. To si bere sini korin ton tele awon ofin wa, sugbon lesekese na osi yipada. Tio le tesiwaju mo. Fun awon idi kan tabi keji, kole tesiwaju mo. Bhagavata sowipe, " Kilode gan to ba yipda?" Seri bayi. Toba tie yipada nitoripe ko logbon to pe ninu imoye Krsna, kole kuna. Bhāgavata sowipe, ko vārtha āpto 'bhajatāṁ sva-dharmataḥ. Kini ijeere to ma gba teyan ba sise re daju daju? Ipadanu loje fun nitoripe ko mo idi fun ile-aye re. Sugbon nibi, eyan to wa pelu wan gan fun ijo kan soso, oti ni imoye yi lara re, ni aye to kan atun bere Ko sor ipadaanu laye re. Abere imoye Krsna kan tito lati je ki aye ye wa ni pipe. asi pada losi ijoba orun. Egbiynaju lati ti egbe yi si waju. sadhana yin niyen, ise inira niyen. Nitoripe egbudo ba orisiri awon eyan. egbudo ba wan ja. Tapasya niyen. eyin si ma faramo awon isokuso ati ebu lati awon eyan wanyi, awon isoro, ema fi gbogbo nkan sile, owo - sugbon kole lo bayi lasan. E fokan bale. Kole lo bayen lasan. Krsna asi jeke jeere, a son pada fun yin niwonba to po gan. E ma sise imoye Krsna yi lo.

Ese pupo.