YO/Prabhupada 0326 - God is the Supreme Father, the Supreme Proprietor, the Supreme Friend



Lecture on BG 2.13 -- Pittsburgh, September 8, 1972

Nisin, bawo ni emi sen fi ara kan le fun ikeji? kasowipe lahin aye yi, mo ni imi to daju. oda gan. Sugbon tinba wo nu awon aye tio da? kasowipe mo ni ara ologbo tabi aja tabi maalu. kasowipe etu pada si orile-ede America. sugbon teba ni ara imi gba, gbogbo nkan to tele na ma yipo. teba je eda, ijob ama toju yin, Sugbon teba gba ara nkna imi bi igi tabi eranko, iyato ma wa bonsen huwa si yin. Awon ran awon eranko losi ile-iperan, wan ge awon igi dannu. Koseni to gbeja wan. Ipo aye yi niyen. Nigbami awon ipo aye to da lama gba, nigbami awon ipo aye tio da lama gba. Kosi iseduro. Bese sise na lema ri gba. Ninu aye yi, teba kawe, ojo iwaju yin ma da. Teyin o ba ka we, ojo iwaji yi o le da. Gege na ale wa ona abayo fu iyika iku ati ibimo yi. Ise kan soso tani ninu aye yi niyen, basele jade kuro ninu awon ipo: Ibimo,iku, ojo arugbo, ati aisan. Ale wa ona-abayo. Imoye Krsna ni ona abayo yi. Lesekese taba ni imoye Krsna.. Itumo imoye Krsna yi ni Krsna, Olorun loje. Nkankanna laje pelu Krsna. Imoye Krsna niyen. Egbiyanju ko bale ye yin. Gege bi Baba yin ati awo aburo yin se ye yin, ati bese ni oye nipa ara yin. Omo baba kan nigbogbo yin. Kole lati ni oye na. gege bi baba sen toju awon ebi re, beena ni Krsna, tabi Olorun, Oni aimoye omo,, awon eda, osin toju gbogbo wan, ebi re. Kilo le nibe? Ise to kan ni lati ni imoye to da. Gege bi omo-okurin, toba ronu pe " baba mi ti se nkna to po funmi. Mo gbudo se nkan fun lati dupe fun gbogbo nkna tose funmi," imoye Krsna ni iru ironu bayi. A ni lati ni oyer nipa nkan met a pere ab fe ni pye nipa Krsna:

bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ
sarva-loka-maheśvaram
suhṛdaṁ sarva-bhūtānāṁ
jñātvā māṁ śāntim ṛcchati
(BG 5.29)

Gbogbo wa lafe ni idunnu. Ija ile aye yi niyen. Sugbon taba ni oye nipa awon nkan meta wanyi, pe Olorun ni Baba wa, Olorun ni Oludari gbogbo nkan, Olorun ni ore wa to gaju, Awon nlan meta wanyi, to ba ye yin, lehin na okan yin ma bale. lesekese. Lesekese. Eyin wa awon ore to po to ma funyin ni iranlowo. Sugbon taba gba Olurun bi ore wa, isoro yin ti ton. Gege na, teba gba Olorun bi Oludari to gaju, isoro wa nitan niyen. Nitoripe awa fe di oludari nkan to je ti Olorun. Awan rowipe ile America yi , pe awon omo-ilu America lon ni; Awon omo-ilu Africa lon ni Africa, " rara. Olorun loni gbogbo ile laaye yi. Omo-Olorun ni gbogbo wa je, pelu aso to yato. Ale gbadun awon nkan Baba wa lai fun elomi ni idamu. gege bi awon ebi wa, ounkoun ti baba wa ati iya wa ba funwa lan je. Awa o le je nkan to wa ninu abo elomi. Iwa tio da niyen. Gege na tawa ba ni imoye Olorun, imoye Krsna, gbogbo isoro aye yi- awujo, esin, oro-aje, ilosiwaju, onisele, - gbogbo loma tan. Otooro niyen. Nitorina lasen gbiyanju lati tesiwaju pelu egbe imoye Krsna yi, fun ijeere gbogbo agbaye eda. Awa si fe ki gbogbo awon eyan to logbon, ni pataki awon omo ile-iwe. kon paarapo pelu egbe ea yi, egbiyanju lati ni oye to daju nipa egbe wa yi. Asi ni awon iwe to po gan, wanto merinle-logun, wansi tobi gan. Ele ka wan, egbiyanju lati ni oye nipa egbe wa yi, ke ni asepo pelu wa.

Ese pupo. Hare Krsna. (Atewo)