YO/Prabhupada 0327 - The Living Being, is Within this Body, the Gross Body and the Subtle Body



Room Conversation -- April 20, 1976, Melbourne

Carol Jarvis: E sofun mi tele pe eyin pa owo repete lati awon iwe yin ten ta lojojumo.

Prabhupada: Beeni.

Carol Jarvis: teyin ba fe ki awon eyan mo nipa nkan teyin ko, kilode teyin sen ta awon iwe yi?

Prabhupada: Bibeko koseni to ma ka. Tin ba fun yin lofe, ema rope, " Ah, iranu leleyi. Wan fun wa lofe."

Carol Jarvis: Beeko, sugbon e le ta fun eye ton fi tewan jade.

Prabhupada: Ton ba sonwo fun, wan femo " Kilo wa ninu awon iwe yi? Eje kin wo na." Teba gba loofe ema toju e sori pepe yin fu aimoye ogorun odun. Sugbon agbudo te awon iwe jade , taloma sonwo fun. Awa o lowo kankan.

Carol Jarvis: Kileyin fi awon owo to ku fise te pa loju titi?

Prabhupada: awan si awon ile- adura to po si. Awan te awon iimi jade si. Iwe mi leleyi. Moti da Egbe iwe Bhaktivedanta sile. O wa ninu iwe pipin ogun mi wpe, kon fi idaji owo ton gba lati fi te awon iwe yi jade. konsi lo idaji iyoku fun ilosiwaju egbe wa. Kosejo ijeere kankan.

Carol Jarvis: Mosi fe mo seyin ni oro kankan fun awon eyan?

Prabhupada: Beeni. Oro ti moni funwa niwipe awon eyan rowipe ara wan lonjre, sugbon iro niyen je. Emi wa ninu ara yi. Gege bi aso teyin wo. Ewa ninu aso yi. Gege na awon eda wa ninu ara yi. Ara mimo wa nkan meta to wa ninu e, okan, ogbon ati imora eni, sugbon ara wa yi, awon nkan lasan lon wan ninu e. iyepe, omi, afefe, ina, bayi bayi lo. Gbogbo e je mejo. agbara to kere leleyi je. sugbon agbara to gaju wa ninu awon nkan mejo wanyi, marun je t'aye yi, meta je t'emi mimo. Agbudo keeko nipa awon nkan wanyi. Gege bi omo-okurin yi se beere pe, " E le daa ero nla ton fo lori afefe, 747, sugbon se le da eni to wa na?