YO/Prabhupada 0331 - Real Happiness is to Go Back to Home, Back to Godhead



Lecture on SB 6.2.16 -- Vrndavana, September 19, 1975

oro to wa nipe enikeni to ba a ninu aye yi, elese ni. enikeni. bibeko kole ni ara yi. gege bi awon ton ba wa ninu ewon, ele so wipe, odaran niwan. Ko wulo ke ma wo wan leyo kankan. nitoripe o wa ninu ewon, ele sowipe " Odaran leleyi" gege na enikeni toba wa ninu ile-aye yi, odaran ni. sugbon olopa ni ewon yato. eyin o le sowipe nitoripe gbogbo eyan to wa ninu ewo odaran niwan, gege na olopa ga odaran loje." Eti s'asise niyen. Awon ton sise lati mu awon odaran wanyi pada si ijoba orun odaran koni wan. Lati fun awon asiwere wanyi nigbala ni ise re. lehin asi mu wan pada losi ile Olorun.

gege na mahad-vicalanaṁ nṛṇāṁ gṛhiṇāṁ dīna-cetasāṁ. Gṛhiṇāṁ. enikeni ton gbe ninu ile-aye yi tabi ninu ara yi lon pe ni Grhi. Nkan to kere gan ni, nitorin lokan wan o se da. Wan o mo idi fun aye yi. Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇum (SB 7.5.31). dipo ton ma wa nkan toma fun wa ni imoye, mahat tabi mahatma, wan duro sinu okunkun, sugbon agbudo funwan ni imoye yi. lati se waasu pe ema joko sinu ile-aye yi ni ise tonni. Ewa ni ijoba orun." Ise mahatama niyen. Mahad-vicalanaṁ nṛṇāṁ gṛhiṇāṁ dīna-cetasām. Awon eyan yi o logbon, mudha. wanti salaaye pe mūḍha, duṣkṛtina niwan. awon ton se iranu nitori aimokan . teba sowipe " rara, bawo lesele sowipe wan o mo nkankan? Ile-iwe eko giga towa po gan. wan jad pelu M.A.C, D.A.C, dokita, Ph.D sugbon wan o mo nkankan?" Beeni. Bawo? Māyayāpahṛta-jñānā: maya ti gba ogb on iranu ton ni" Bibeko kilode tonse wa ninu ile aye yi? Teyin ba logbon egbudo mo, wipe ile-aye o se ibi teyan le gbe. Agbudo pada si ihjoba orun. Nitorin ni egbe imoye Krsna yi sen se iwaasu pe " Ile yin kolele yi. Ema seto ati ni idunnu nibi." Durāśayā ye bahir-artha-māninaḥ. Bahir-artha-māninaḥ. Bahir, agbara ita. wan ronu pe tinba seto bayi bayi... awon imi fe ni idunnu lati ilosiwaju ninu sayensi, awon imi fe lo si awon isogbe orun, awon imi fe di tibi, toun, sugbon wan o me wipe idunnu gidi towa ni wipe agudo pada si ijoba oorun. Na te viduḥ svārtha-gatiṁ hi viṣṇum (SB 7.5.31). wan o mo be. gege na egbe to se pataki gan leleyi, awa si fe kon mo, asi fe fun wa leeko, bonsele pada si ijoba Orun. Ese pupo.