YO/Prabhupada 0332 - There can be Very Peaceful Condition of the Whole World



Room Conversation -- April 27, 1976, Auckland, New Zealand

alaafia to po le wa ninu ile-aye yi. sugbon awon oniranu ti ba gbogbo nkan je. bibeko, awon eyan le gbe lalaafia, kon si jeun dada, kon loasiko wan dada, koded sejo pe efe fi ipaari si awon nkan patako aye. eto wan fun jijeun, sisun, imo ako ati abo na. sugbon bi awon were ati ode ko, bi awon eyan to logbon. sugbon awujo ile aye isin, awujo iranu loje. Igbadun die to wa ninu imo ako ati abo - wan kan fe ma se lo, Were leleyi. Jijeun - E je ounkoun, iranu, kedi elede. Sisun- Oh, e sun besefe, nigbagbogbo teba fe. nkan ton sele niyen. Jijeun, sisun, imo-ako ati abo, ati igeja ara eni- wansi da awon ohun ogun wan si pa awon eyna danu. Nkan ton sele niyen. Sugbon wan le lo gbobo awon nkan wanyi dada fu alaafia, teba de ni alaafia, laisi idanmu, lehin na ele korin Hare Krsna, ile-aye yin asi ni ilosiwaju. Ise wa leleyi. Awa o fe fi ipaari si nkankan. Bawo laseke fi ipaari si? gege bi awa se ti gba sannyasa. Kini yen> " Awa ni se imo ako ati abo mo, bibeko awa na jeuin, awa na sun." iyen na ma tan taba darugbo si. Teba darugbo bi emi nisin, teto omo odun ogorin, tin ba fe ni imo ako ati abo, so jo nkan to da? Awon omo-okurin wan le se, ko si wahala. Sugbon arugbo ton lo si ile ijo, ton na wo funimo ako ati abo. Nitorina ni aye grhastha se wa lati odun marun lelogun titi di aadota. Otan Lehin na efi ipaari si imo ako ati abo. Niotooro, awon eyan yi fe fi ipaari si awon eyan. Kilode ton sen ni imo ako ati abo yi? Rara, wan ni asepo yi, lehin na wan pa awon omode yi. Kini yen? Ile aye ese. Wan ma jiya, wan ma jiya lo titi. Awa fe fi ipaari si gbogbo ijiya wanyi. Awon asiwere wanyi o le mo. wan rowipe, " Egbe imoye Krsna yi funwa ni idaamu." Awujo awon oniranu. Agbudo gbiyanju. Kilale se? Eyin na sin ranwa lowo. Ema ba egbe yi je pelu awon irori iranu. Ema se bayi. E ma se gege basense, e je ki ara yin wa mimo, lehinna o daju pe egbe yi ma ni ilosiwaju. Sugbon teyin ba fe baaje, pelu iranu teyin se, kilafe se nigbana> Oma baje. teyin ba da iranu sile, te bere sini ja pelu ara yin, a kon dabi awon egbe iyoku. Agbara re ma tan. Egbudo ranti Nisin, awon eyna gan fe mo, o ya wan lenu: Kini orin Hare Krsna yi to si lagbara lati yi awaon eyan pada?" Lowo keji agbudo gbawipe, afi to baje pe o l'agbara, bawo lo sen sise? Agbudp toju agbara yi. Ema so si orin lasan. Nkan imi loje, nkan mimo. O dabi orin lasan sugbon o lagbara gan. Mantrauśadhi-vaśa. Pelu mantra eyan le ni idari lori awon ejo. gege na ele mowipeorin lasan ko ni mantra je. Agbudo toju agbara mantra yi, lai se taban korin a. teba fi idoti pa mantra na, agbara re ma tan.