YO/Prabhupada 0334 - The Real Necessity of Life is to Supply the Comforts of the Soul



Lecture on SB 1.8.33 -- Los Angeles, April 25, 1972

Igbadun ara yi o le fun yin nigbala. Kaso wipe okurin kan wa ton gbadun. se iyen wipe koni ku? O ma ku. Awon igbadun ara yi o le fun yin ni gbadun. tiraka ile aye yi. tiraka ile aye yi. taba kan toju ara wa, nkan ton pe ni dharmasya glanih niyen, iranu. Eyan gbudo mo iyato laarin awon nkan kosemanni fun ara wa ati awon nkan kosemaani fun emi wa. Nkan to se pataki ju ni awon nkan kosemaani fun emi wa. awon nkan aye yi o le fun emi wa ni idunnu kankan. nitoripe nkan imi tayato l'emi wa je, agbudo fun lounje mimo. imoye Krsna yi ni ounje mimo na teba fun emi wa ni ounje mimo...

awon ounje imi wa tele fun ein tara re oba ya. Awon nkan imeji lowa. teba fun loogun lai fun lounje to da, kole sise. Gege na egbe imoye Krsna yi wa lati fun awon eyan ni ounje to da ati ogun to da, fun emi wan. Ogun yi wa ninu maha mantra Hare Krsna. Bhavauṣadhāc chrotra-mano-'bhirāmāt ka uttamaśloka-guṇānuvādāt pumān virajyeta vinā paśughnāt (SB 10.1.4). Parīkṣit Mahārāja sofun Śukadeva Gosvāmī pe: " Oro Bhagavata to funmi yi kon se nkan lasan." Nivṛtta-tarṣair upagīyamānāt. Awon eyan nivṛtta-tṛṣṇā lon le gbadun awon eto Bhagavata yi. aniyan nitumo Tṛṣṇā, tṛṣṇā. gbogbo eyan ninu aye yi lo ni aniyan. awon eyan tio ni aniyan wanyi lon le mo nipa Bhagavata, bo se dunto. Nkan to da gan loje. Nivṛtta-tarṣaiḥ... Gege na Hare Krsna mantra yi, bhagavata na loje. ounkoun toni asepo pelu Eledumare. bhagavata loje. Bhagavan ni oruko Eledumare. Bhagavata-śabda, awon nkan to ni asepo pelu re, ounkoun, Bhagavata-śabda yi ma di bhagavata-śabda.

Parīkṣit Mahārāja ti sowipe itowo Bhagavata yi, eni toba ti se tan pelu aawon aniyan ile-aye yi lole towo. Nivṛtta-tarṣair upagīyamānāt. Kilode to ye towo? Bhavauṣadhi. Bhavauṣadhi, ogun fun aisan ibimo ati iku. "a di" nitumo Bhava. lasiko tawayi awa sini aisan. Awon eyan yi o mo nkan ti aisan je tabi nkna ti ara to wa lalaafia je, awon asiwere wanyi. Wan o mo nkankan sugbon wan si pe ara wa ni alakowe, onisayensi.. Wan o le beere pe : " Mio fe ku. Sugbon iku asi pa mi?" Kosi ibeere kankan b ayi. Kode si ona abayo kankan. Wansi pe rawan ni ona abayo.Iru awon oni sayensi wo lelelyi? Itumo sayensi niwipe a logbon, e le din awon isoro aye yin ku. sayensi niyen. Bibeko, kini sayensi? wan kan fun awon eyan l'adehun pe , "lojo waju." Sugbon kileyin sen nisin sa? " Eyin jiya nisin,sugbon e fe ka gbawipe lojowaju ema sen nkan. Rara. ātyantika-duḥkha-nivṛtti. Ātyantika, pipe. pipi niumo Ātyantika Ijiya nitumo Duḥkha. Ipo aye wa niyen. awon eyan o mo nkan ti ātyantika-duḥkha yi je. Ijiya nitumo Duḥkh. Wanti juwe nipa ātyantika-duḥkha ninu Bhagavad-gītā. ātyantika-duḥkha leleyi sa. Kilo je? Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi (BG 13.9) Ibimo, iku, ojo-arugbo ati aisan.