YO/Prabhupada 0337 - Don't Waste Your Time Bothering about this So-called Happiness and Distress



Lecture on CC Madhya-lila 20.103 -- Washington, D.C., July 8, 1976

nkan orisirisi lo wa toam fun wa niidamu. tiraka to wa niye niun ile aye yi. alafia to wa o po. Ibeere kanna ni Sanatana Gosvami beer, kioode ti gbogbo tiraka yi se wa? Kilode ti aye o ye rorun? Kilode ti awon nkan imi fun wa ni isoro to po? Mofe ki indu mi dun, sugbon idamu po. Idamu ninu ile aye yi. Ibeere to wa niwipe: Kilode? agbudo ba awon esinsin gan ja, awonn esinsin asi fun wa niidamu. Wan po gan. teba tie joko lai se nkankan. gege bi okurin ton rin loju titi lai se nkankan, sugbon niwaju ile kan, awon aja a bere sini gbo: " Kilode to sen wa sibi? Nibo lotin bo?" Kosidi fu lati ma gbo, sugbon nitoripe aja loje, ise re niyen "kilode tosen wa sibi, kilode tonse wa sibi?" Gege an awa na sini ominiran lati losi ibikibi to bawunwa awon onise isiwa: " Kilode teo se wa? Kilode to se wa?" Ni opolopo awon ibi, wanti sofun wa ka ma wle. wanti da apada lori oko afefe. "Rara, eyin o le wole, e pada."£ Gege na mosi pada, orisirisi isoro. Padaṁ padaṁ yad vipadāṁ na teṣām (SB 10.14.58). ninu ile-aye yi, kosi besele gbe lalafia. kos'alafia kankan. Isoro to po gan wa. Sastra ti sowipe, padaṁ padaṁ yad vipadām: alebu wa ninu gbogbo nkan ta ban se. lati awon eranko nikanko, lati awon eyan na, lati iseda, kode si nkankan talese. gege bayi ile aye wa ninu aye yi o da, awa gbudo bere wipe kilode ti awon isoro wanyi wa. Ile-aye yi eyan niyen. ile-aye eyan niyen.

Bawo lese le beere? Bawo lase fe ni idunnu? Kini Ipinnu aye yi? Sanātana Gosvāmī... oun ni kan ko, ti salaye funwa. Awa o mo, awa o mo. pelu ore-ofe Caitanya Mahaprabhu tabi ore-ofe awon iranse re, ale mo nipa nkan ti ipo aye yi je, kilode ta sen tiraka, kilode tiku se wa. Mio fe ku; kilode ti ibimo se wa? Mio fe wonu ikun iya kankan ma, lati wa fun po fun osu to po. Mio fe darugbo; sugbon awon nkan wanyi sin sele simi. Nitorina ise gidi tani ni basele fi ipaari si awon ibeere waniy, kon se lati seto oro aje. Eto oro aje, oukoun toba ye ka gba lama ri gba laye yi. Idunnu tabi ibanuje, a ma rigba. gege bi awa o se kin wa ibanuje, sugbon oma fun ara re wa bawa. gege na awon idunnu toye ka ri gba na mawa. Ilana sastra niyen. Ema lo asiko yi ni ilokulo pe eyin idunnu. idunnu toba yeke gba lema rigba, oma wa fun ara re. Bawo lose ma wa? Yathā duḥkham ayatnataḥ. Ona kanna. gege bi eyin o kin wa ibanuju sugbon o ma wa fun ara re. Gege na teyin o ba sise fun idunnu, oma wa fun ara re. Ema loasiko yin nilokulo nipa iduunu tabi ibanuje. elo asiko yin ninu eto lati monipa ipinnu aye yi. kilode ti awon isoro se po bayi, kilode ta senn tiraka ninu aye yi. Ise yin niyen... Egbe imoye Krsna yi fe ki awon eyan mo nipa awon isoro wanyi. Kon se egbe kegebe, tab'esin. Egbe ikeko asa loje. Gbogbo eyan gbudo monipa ipinnu aye yi. gbogbo eyan gbuod mo kilode ti asen tiraka lati legbe, se ona obayo kankan wa, tale gbe lalaafia laisi isoro wanyi Nkan toye ki awon eyan ma ko leleyi gege bi Sanātana Gosvāmī, to je eyan patai ni ijoba, osi lo ba Caitanya Mahaprabhu. Agbudo loba Caitanya Mahaprabhu tabi awon ojise re,kasi teriba. Tad viddhi praṇipātena (BG 4.34). konsepe kalo ma sagidi, " So lofi Olorun han mi?" Agidi leleyi.Bayi ko. Olorun wa nibikibi, sugbon egudo ni ouj lati ri Olrun na, lehin na ele sowipe, " Fi olorun han mi?" Iwa yi ma ranwa lowo. E teriba. Tad viddhi praṇipātena. Oror sastra iyen. Teba ni oye nipa sayensi yi, sayensi to gaju, tad viddhi - egbiyanju ke mo- sugbon pranipatena, e resile. gege bi Sanatana Gosvai se resile.