YO/Prabhupada 0340 - You are not Meant for Death, but Nature is Forcing You



Lecture on BG 9.1 -- Melbourne, June 29, 1974

namo mahā-vadānyāya
kṛṣṇa-prema-pradāya te
kṛṣṇāya kṛṣṇa-caitanya-
nāmne gaura-tviṣe namaḥ
(CC Madhya 19.53)

Śrīla Rūpa Gosvāmī, nigbato ba Śrī Caitanya Mahāprabhu ni Prayāg… oni ibi kan toje mimo ni orile-ede India ton pe ni Prayaga. Lehin igbati Śrī Caitanya Mahāprabhu, ti gba sannyasa ton, o lo si Prayaga ato awon ibi mimo na. nigbana Śrīla Rūpa Gosvāmī, ni alakoso ninu ijoba, sugbon osi fi gbogbo e sile lati bosinu egbe imoye Krsna yi pelu Śrī Caitanya Mahāprabhu. nigba ton koko pade lo si ka ese iwe yi fun, namo mahā-vadānyāya. itumo Vadanyaya ni eni ti ore-ofe re gaju." Orisirisi iranse Olorun lowa, sugbon Rupa Gosvami sowipe, " Sri Caitanya Mahaprabhu loni ore-ofe to gaju." Namo mahā-vadānyāya. Kilode to se gaju? Kṛṣṇa-prema-pradāya te: " eyin fu awon eyan ni Krsna pelu egbe sankirtana yi."

Latri ni oye nipa Krsna, ise to le gan ni. Kṛṣṇa ti so fu ara re ninu Bhagavad-gītā,

manuṣyāṇāṁ sahasreṣu
kaścid yatati siddhaye
(BG 7.3)

ninu aimoye awon eyan, lasiko tawayi, lai atijo na. Manuṣyāṇāṁ sahasreṣu, "ninu aimoye awon eyan, "kaścid yatati siddhaye, "boya ikan ninu wa ma di pipe." awon wanyi o monipa nkan ti aye pipe je. Itunmo aye pipe niwipe wan fi ipari si ibimo, iku, ojo arugbo ati aisan. Nkan ton pe ni pipe niyen. Gbogob eyan lofe wa ni pipe, wan o mo nkan ti pipe je. itunmo re ni iwpe: eyin ti bo lowo awon alebu merin wanyi.; Kini yen? Ibimo, iku, ojo -arugbo ati aisan. Gbogbo eyan. Koseni tofe ku, sugbon wan gbudo ku. Alebu niyen je. Sugbon awon asiwere wanyi o mo. Wan rowipw agbudo ku. Bee ko. Nitoripe eda tayeraye leje eyin o gbudo ku, sugbon iseda yi ti se ni dandan pe ke ku.