YO/Prabhupada 0347 - First of all you Take your Birth where Krishna is now Present



Lecture on BG 2.14 -- Mexico, February 14, 1975

Hṛdayānanda: tawa ba yasi mimo, sale monipa ibasepo wo lani pelu Olorun?

Prabhupada: Beeni, eto iyasi mimo niyen.

Hṛdayānanda: (Spanish)

Hanumān: Prabhupāda, mofe o tio ba si ibimo ninu ijoba orun, bawo lase fe pada si ijoba orun?

Prabhupada: Hm? Itunmo Ibimo ni wipe, ni alakoko eyin ma ni ibimo yin nibi ti Krsna ba wa nisin. Krsna wa ninu ikan ninu awon agbaye wan yi, aimoye agbaye to wa. Gege na ema ni ibimo yin ninu agbaye ti Krsna ba wa nisin. Lehin na wa ko yi leeko, lehin na le pada fun ra yin si Vaikuntha. Kosejo ibimo. Hm,Kini yen?

Hṛdayānanda: Ibeere ati idaaun si?

Prabhupada: teba fe, mo le tesiwaju si.

Hrdayananda: Se ona imi wa lati pada si Olorun,

Prabhpada: Rara (erin) nitoripe Bhagavad-gita ti salaaye,

bhaktyā mām abhijānāti
yāvān yaś cāsmi tattvataḥ
tato māṁ tattvato jñātvā
viśate tad-anantaram
(BG 18.55)

e waadi eleyi, bhaktyā mām abhijānāti.

Hṛdayānanda:

bhaktyā mām abhijānāti
yāvān yaś cāsmi tattvataḥ
tato māṁ tattvato jñātvā
viśate tad-anantaram
(BG 18.55)

Prabhupada: Koseni tole wonu Ijoba Olorun lai bhata (Isinmi) Kode si nkan to le lati di bhakta nitoripe.. Ofin merin nitumo pe edi bhakta. Egbudo ronu nipa Krsna ni gbogbo igba. Man-manā bhava mad-bhaktaḥ. bhakta niyen. E kon ronu nipa Krsna. Hare Krsna niyen. teyin ba korin Hare Krsna,teyin ba ronu nipa Krsna, Ema di bhakta lesekese. lehin teba ti di man-manā bhava, mad-yājī: "E ma sadura si," māṁ namaskuru, " ema teriba fun." Nkan to rorun gan loje. Teba ronu re, te teriba fun, te s'adura si, awon nkan met awany a so yin di Bhakata, lehin n a ema pada losi Ijoba Orun. Nkan tawan ko leleyi: Ekorin Hare Krsna, e teriba si irisis Olorun, et sadura ISe ton niyen.

Hṛdayānanda: (Spanish)

Prabhupada: KIlode to ye ko gba ona jnana? wan gbudo kawo gan, awon orisirisi. Efi awon nkan wanyi sile, ke se awon nkan meta wanyi o tan, ema di bhakta. Kilode teyin o se fe gba ona to rorun gan lati pada si ijoba orun? Ese Pupo.