YO/Prabhupada 0349 - I Simply Believed what was Spoken by My Guru Maharaja



Arrival Address -- New York, July 9, 1976

gege na awon to logobn gbudo mo nipa awon orisirisi ipo aye. Sugbon wan o mo. Nijoto koja Dr. Svarupa Damodara sin soro, pe gbogbo ilosiwaju tonni ninu etoo sayensi tabi ikeeko, nkan meeji si ku. Wan o mo nkan ti awon isogbe orisirisi yi je Wankan fori ro. Wan fe lo sori osupa, kolese se. teba tie losi isogbe kan si keji, kile mo nipa wan? kosi imoye kankan. Wan o mo nkan toje isoro aye yi. awon nkan meji yi ni wan o ni. Awa sin seto wan. Isoro aye yi niwipe awa o ni nkankan, awa ti kuro ninu imoye krsna,nitorina la sen jiya. teba si gba imoye Krsna yi, gbogbo isoro yi ma tan. ati eto awon isogbe orun, Krsna si ti funwa l'aaye lati losiibikibi tabafe. awon eyan ton logbon wa mu mad-yājino 'pi yānti mām (BG 9.25). " awon ton ni imoye Krsna wan pada sodo mi." KIni iyato laarin awon meejeji yi? Tin ba tie losi osupa tabi Marsatabi Brahmaloka, Kṛṣṇa sowipe, ā-brahma-bhuvanāl lokāḥ punar āvartino 'rjuna (BG 8.16). Ele losi Brahmaloka sugbon kṣīṇe puṇye puṇyo martya-lokaṁ viśanti:" ema tun pada wa." Kṛṣṇa sisowipe, yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6). Mad-yājino 'pi yānti mām.

eti ni ayee yi, imoye Krsna yi. wanti salaaye gbogbo nkan ninu Bhagavad-gita,ema soonu. ema huwa bi ode, ema jeki awon onisayensi tan yin je, tabiawon oniselu. Egba imoye Krsna yi o sese pelu guru-kṛṣṇa-kṛpāya (CC Madhya 19.151). pelu ore-ofe gur ati Krsna ele ni ilosiwaju. Asiri to wa niyen.

yasya deve parā bhaktir
yathā deve tathā gurau
tasyaite kathitā hy arthāḥ
prakāśante mahātmanaḥ
(ŚU 6.23)

gege na guru-pūjā tawan se, kon se nkan igberaga; ikeeko gidi leleyi. Eyin korin lojojum na, kiniyen? Guru-mukha-padma-vākya... āra nā kariyā aikya. Bas, isotunmo to wa niyen. Niotoro, ilosiwaju kankan toba wa ninu egbe imoye Krsna yi, O dami loju pe Guru Maharaja mi loso. Teyin ma tesiwaju bayi. Lehina gbogbo nkan ma da. Ese pupo.