YO/Prabhupada 0350 - We are Trying to Make the People Qualified to see Krishna



Lecture on BG 7.2 -- Nairobi, October 28, 1975

Brahmānanda: O sowipe lati Veda a le mowipe alalopin ni Krsna je, nipataki nigbaton se rasa-lila pelu awon gopi. gege na ti alailopin ni Krsna, kilode ti o....?

Okurin India: se fara re han si gbogbo agbaye ki gbogbo baale pada si ijoba orun?

Brahmananda: kilode ti kose fara re han si gbogbo agbaye ki gbogbo baale pada si ijoba orun?

Prabhpada: Beeni, oti farare han ni gbogbo agbaye sugbn eyin o leri. Alebu teyin ni niyen. Krsna wa nibikibi. Sugbon bi orun se wa ni ofurufu, ilode teyin o se leri nisin? Huh? E daaun. Seyin rowipe Orun o si mo ni afefe? Seyin rope orun ti lo? E lo sori oke ile yin ke lo wo orun na. (Erin) Kilode tefe ki gbogbo eyan mo pe oniranu niyin pe " Rara, rara, kos'orun? se awon alakowe ma gba? Nitoripe eyin o le ri orun nitorina ko s'orun? Se awon alakowe magba? Lale eyin o le foju ri orun, teba sofun alakowe to mo nipa awon nkna wanyi, Rara, rara, ko s'orun< so ma gba? A sowipe " Orun wa. Oniranu yi, iwo lole ri." Otan. "Teba jade kuro ninu iranu ten se. Lehin na emari." Nāhaṁ prakāśaḥ sarvasya yoga-māyā-samāvṛtaḥ (BG 7.25), Kṛṣṇa sobe. Awon oniran o le foju ri, sugbon awon ton mo, wan le ri.

premāñjana-cchurita-bhakti-vilocanena
santaḥ sadaiva hṛdayeṣu vilokayanti
yaṁ śyāmasundaram acintya-guṇa...
(Bs. 5.38)

awon elesin man ri Krsna nigbogbo igba, Fun etan bayi, owa nigbogbo igba. fun awon oniranu. Wan ole ri. Iyato to wa niyen. Egbudo di aawon to daju, lehin na ele ri. Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe arjuna tiṣṭhati (BG 18.61). Krsna wa ninu okan gbogbo eyan. seyin mobe. sele ri? Sele ba soro? O wa ninu okan yin, o wa nbe. Sugbon talon ba soro? Teṣāṁ satata-yuktānāṁ bhajatāṁ prīti-pūrvakam, dadāmi buddhi-yogaṁ tam (BG 10.10). On ba awon elesin ton sise fun wakati merinle-l'ogun Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita. Seyin o ti ka Bhagavad-gita? Gbogbo nkna loni amuye toye. Itumo egbe imoye Krsna yi niwipe a fe jeki awon eyan ni amuye tye lati ri Krsna. Lai ni awon amuye wanyi, bawo lese fe ri? egbudo ni awon auye wanyi.