YO/Prabhupada 0359 - One has to Learn this Science from the Parampara System



Lecture on BG 4.2 -- Bombay, March 22, 1974

Itumo imoye Veda ni lati ni oye nipa Krsna. sugbon teyin o ba ni oye nipa Krsna teyin kon so isokuso, tesi pe rayin ni pandita, śrama eva hi kevalam niyen. śrama eva hi. ilokulo asiko wa niyen. Vāsudeve bhagavati...

dharmaḥ svanuṣṭhitaḥ puṁsāṁ
viṣvaksena-kathāsu yaḥ
notpādayed yadi ratiṁ
śrama eva hi kevalam
(SB 1.2.8)

gbogbo wa lan sise wa dada. Brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra. Mon ba awujo awon eyan gidi soro, awon erank ko. ninu awon awujo to daju, awon brahmana n'sise wan. Satyaṁ śamo damas titikṣā ārjavam, jñānaṁ vijñānam āstikyaṁ brahma-karma svabhāva-jam (BG 18.42). Dharmaḥ svanuṣṭhitaḥ, osi nsise re bi brahmana, sugbon teyan ban sise wanyi ti o ba ni imoye Krsna, śrama eva hi kevalam. Bose je niyen. Ilokulo asiko loje. nitoripe ati brahmana, itumo re niwipw agbudo mo nipa Brahman. Athāto brahma jijñāsā. ati Para-brahman, Brahman to gaju i Krsna. gege na ti ko ba mo ni pa Krsna kini iwulo pe oun sise brahmana. Oro sastra niyen. Śrama eva hi kevalam, ilpkulo asiko.

Nitorina agbudo ko sayensi yi lati ilana parampara. Evaṁ paramparā-prāptam (BG 4.2). egbudo loba ei to daju to mo Krsna. Evaṁ paramparā... gege bi Surya, Vivasvan, Krsna losi ko wan. Gege na teba gba imoye na lati orisa-orun, eti ni imoue to daju niyen. Sugbon eyin o le losi Orun lati lo beere lowo Vivasvan, " Kini Krsna sofun e?" Nitorina ni Vivasvan se soro na fun omo re, Manu. Asiko yi Vaivasvata Manu loje. Nitoripe o je omo Visvasvan lonse pe ni Vaisvasvata Manu. Vaivasvata Manu. Asiko tin koja fun Vaivasvata Manu. Manur ikṣvākave 'bravīt. Manu na salaaye fun omo re. Gege na evaṁ paramparā-prāptam (BG 4.2), oti fun wa l'apeere pe agbudo gba impye yi lati parampara. Sugbon bakanna, parampara yi ti sonu... gege bi mose sofun awon akeko mi. asi so nkankanna si akeko re, oun a sofun akeko re. sugbon ti bakanna imoye yi ba yipo, oma sonu lesekese ti ikan ninu awon akeko na ba fi tie kun imoye, o ma sonu. Wanti salaaye.

Sa kālena mahatā. Asiko si lagbara gan. Nitori asiko ton koja ni imoye na sen yi kuro lati boseje. Eyin na le jerisi, teba ra nkan. O le dara ga, sugbon lehin igba die abere sini ku asi darugbo, lehin igba die koni se lo mo Asiko n'ba wa ja. Asiko ile aye yi kala. Iku nitumo kala tabi ejo dudu. Ejo dudu asi ba gbogbo nkan je,lesekese ti nkan ba summo. Otan niyen Gege na kala...oruko imi fun Krsna niyen. kālena mahatā. nitorina lonsen pe ni mahata, O lagbara gan. Nkan lasan ko loje. Mahata. Lati ba awon nkan je ni ise to ni. Sa kālena iha naṣṭa. bawo ni kala sen ba nkan je? Lesekese ti Kala ba ripe eyin tin fi nkan kun oma sonu. Ema gbiyanju lati gbo Bhagavad-gota lowo awon eyan ton labe kala - ojo eyin, isin, ojo iwaju. Ema gbo Bhagavad-gita lowo awon oniranu wanyi, tabi alakowe Wan ko Bhagavad-gita yi ni ona tio da. Enikan ma sowipe, " Kosesni ton pe ni Krsna, Kosi Mahabharata." Elomi asowipe, " Krsna soro lori nkan bayi bayi, Elomi asowipe, Krsna soro lori karma, karma-kanda." Elomi a sowipe jnana, elommi a sowipe yoga. Orisirisi isotunmo lowa fun Bhagavad-gita. Yogī cārtha, jñāna artha, Gītār gān artha... Olorun ti fun wa ni Gītār Gān agbudo gba gbe. Gītār Gān niyen.