YO/Prabhupada 0360 - We don't Approach Krishna Directly. We must Begin our Service to Krishna's Servant



Lecture on SB 7.9.42 -- Mayapur, March 22, 1976

nibi, ko nu atra te akhila-guro bhagavan prayāsa. gbogbo wa lasi ni lati gba nkan toma je ka sise si, sugbon Krsna o ri be. Krsna niyen. O le se bose wun. Ko gbekele enikeni. awon elomi lo gbekele Krsna, sugobn Krsna le se bosen fe. Nitorina ni Prahlāda Mahārāja se sowipe bhagavan prayāsa. Prayasa, awo elesin o gbudo gba. Eyan ogbudo ise kankan to ni isoro to po. rara. Oye ka se awon nkan to rorun sugbon awon elesin le sise pelu alebu gege bi Hanuman. Iranse Oluwa Ramacandra loje. Oluwa Rāmacandra si fe gbo iroyin nipa Sītādevi. Gege na ko bere sini ronu pe bawo ni mose fe losodi keji okun lanka? O kan ni gbagbo ninu Oluwa Rāmacandra, "Jaya Rama, ode fo koja. Nigbati Rāmacandra fe ko afara. afara yi da nitoripe awon obo yin ranlowo pelu okuta, wande ju sinu omi, okuta na si lefo lori omi. nibo ni ofin gravitation yin lo? eh? Okuta to llefo lori omi. Awon oni sayensi o le se. Sugbon pelu ironu Oluwa Ramacandra, okuta na bere sini fo lori omi. bibeko adura okuta wo lon ma ju sinu omi koto de ipo afara Olese se, gbogbo nkan lose se, sugbon Ramacandra si fe ko rorun, Eje kon mu okut awa, asi lefo lori omi. Lehin a ma koja." laisi okuta gan ole koja , sugbon osi fe kiawon abo na sise fun. awon obo to po gan lowa. Baro baro badare, baro baro peṭ, laṅka diṅgake, mata kare het. Awon obo twa si pogan sugbon gbogbo wan ko lon lagbara bi Hanuman. Nitorina wan si fu wa laaye lati mu okuta wa. Eyin o le fo ori okun koja bi Hanuman. emu okuta wa masi jeko lefo lori omi."

Gege na Krsna le se ounkooun. Aṅgāni yasya sakalendriya-vṛttimanti O le se bose wun. Awa o le se kama bere ore-ofe re. gege na Prahlada Maharaja si bere " teba si aanu fun wa, kon se kan to le fun yin nitoripe ele se oukoun teba fe nitoripe Eyin ni idi fun iseda, titoju e ati ipaari re, kole fun e." lehin iyen na, mūḍheṣu vai mahad-anugraha ārta-bandho. awon ton je ārta-bandhu, , ore si won awujo ton jiya, wan kan ma saanu fun awon mudha wan yi, awon asiwere. Nitorina ni Krsna sen wa, mudha ni gbogbo wa je. Duṣkṛtino. Na māṁ duṣkṭtino mūḍhāḥ prapadyante. Elese nigbogbo wa nitoripe mudha laje, awa o fe teriba fun Krsna. Na māṁ prapadyante. enikei tio ba fe teriba fun Krsna, duṣkṛtina, mūḍha, narādhamā, māyayāpahṛta-jñānā ni eyan na je. Kosi besele se nkan to wunyin lasi si Krsna. awon tonfe sise laisi Krsna, mudha, asiwere niwan wan o fe gba nkan ti Krsna baso, wansi fe da nkan wa sile. Kosi iwulo fun Olorun Awon ni sayeni lon soro bayi, Nisin ati ni sayensi ale se bose wuwa, mudha lonje, kole se se. Eyin o le se nkankan laisi Krsna. Egbiyanju lati wa ore-ofe Krsan nigbogbo igba eyin o sile gba ore-ofe Krsna fun ara yin. Nkan imi to wa niyen. Kiṁ tena te priya-janān anusevatāṁ naḥ. eyin o le fo koja si Krsna lai gba ore-of awon elesin re na. Yasya prasādād bhagavat-prasādaḥ. Eyin o le lo ba Bhagavan fun ara re. Iranu imi tun le leleyi, egbudo gba ore-ofe awon elesin Krsna na. Gopī-bhartur pada-kamalayor dāsa-dāsa-dāsānudāsaḥ. Bi ilana wa se ri niyen. Awa o kin lo gba Krsna fun ara wa. Agbudo bere ise yi si awon iranse Krsna. tani iranse Krsna?Enito ti di iranse fun iranse Krsna. nkan to pe ni dāsa-dāsānudāsa. Koseni to le danikan di ranse Krsna. Iranu imi to tun wa niyen. Krsna o le gba enikankan fun ara re. Kolese se. Egbudo tele ilana awon iranse (CC Madhya 13.80). nkan ton pe ni ilana Parampara niyen. gege bese ma gba imoye na lati Parampara. Krsna sofun Brahma, Brahma sofun Narada, HNarada sofun Vyasadeva, lehin na awa sen r imoye yi gba. Gege bi Krsna... Krsna salaaye Bhagavad-gita si Arjuna. gege na tawa ba fi ilana imoye yi sile gege bi Arjuna se se, lehin na kosi besele ni oye nipa Krsna tabi Olorun. Kolese se . Egbudo gba ilan ti Arjuna gba. Arjuna sowipe moti gba yin , eyin ni Eledumare, nitoripe Vyasadeva ti gba, Asita ti gba, Narada na ti gba2> Nkankan na loje. Agbudo ni oye nipa Krsna. Awa o le mo ni pa re fun ara wa. Awon asiwere wanyi to fe ni oye nipa Krsna lati awon isotunmo asiwere ni gbogbo wan. kosi bon sele ni oye nipa Krsna, enikeni tiko baa je. Koseni to se pataki Śva-viḍ-varāhoṣṭra-kharaiḥ saṁstutaḥ puruṣaḥ paśuḥ (SB 2.3.19). Puruṣaḥ paśuḥ. awon eyan pataki wanyi ti awon ko yin logo lasan, tolon je? Nitoripe wan o kin se elesin Krsna, kosi bonsele di olori. Wan kan po awon eyan ninu. Nitorina asiwere ni gbogbo wan. Amuye to gbudo wan niyen. Egba bee. Ounkoun teba fe ko lateyan o wo na teyan na ba je elesin Krsna. BIbeko ema se. Awa o kin gba ikeeko kankan lowo awon eyan. Awa o fe iru aawon oni sayensi wanyi. rara. Enitoba mo Krsna, Enito ba je elesin Krsna, eniti inu re ban dunsi lati gbo nipa Krsna, ele ko nkan lowo wan. Bibeko, asiwere ni awon iyoku.

Ese pupo