YO/Prabhupada 0363 - Somebody Will be your Friend, and Somebody Will be your Enemy



Lecture on SB 7.9.17 -- Mayapur, February 24, 1976

yasmāt priya apriya-viyoga-saṁyoga-janma-
śokāgninā sakala-yoniṣu dahyamānaḥ
duḥkhauṣadhaṁ tad api duḥkham atad-dhiyāhaṁ
bhūman bhramāmi vada me tava dāsya-yogam
(SB 7.9.17)

ni ese-iwe tokoja Prahlāda Mahārāja, sowipe " mo beru. ipo ile aye yi gan, duḥkhālayam aśāśvatam (BG 8.15). nisin on salaaye nipa awon orisiris ijiya layeyi. yasmāt, lori eto ile-aye yi. taba ti wa sinu aye yi, orisirir ibasepo lawa mani pelu awon eyan to po. Bhūtāpta-pitṛṇām, nṛṇām. lesekese tawa ba jade ninu oyun iya wa, awon ebi to po ma wa, awon ore, bhūta-āpta, pitṛ, bhūtāpta, ṛṣi, pitṛṇām nṛṇām. Atini asepo sugbon awon imi da , awon imi o de da- ota yasmāt priyāpriya-viyoga-samyoga-janma. Viyoga-samyoga-janma. lesekese tonba bi omode asepo re pelu aye tokeyin ma tan, asi ni asepo pelu aye tuntun yi, ara tuntn, viyoga- samyoga. O le jewipe ara to ni kehin si da ju nkan ton gbefun ni aye to wayi. O le ri bayi. Dehāntara-prāptiḥ (BG 2.13). Nigbagbogbo ko le yin ma ni ara to lewa. sugbon agbara itanraeni yi si lagbara to jepe, teyan ba ni ara elede, asi rowipe ara na daa gan. Nkan ton ni prakṣepātmika-śakti. Agbara meji ni maya ni: āvaraṇātmika ati prakṣepātmika. Maya man fi idabo itanraeni fi bowa, sugbon teyan ba ni imoye die, toba de fe jade kuro ninu idinmu maya, agbara imi ton pe ni prakṣepātmika. kasowipe mon ronu wipe " Mofe ni imoye nipa Krsna. Pe imoye ile- aye yi tin funi ni isoro. Ejekin ni imoye Krsna. maya na masowipe, " Kilofe fi se? Oda ko joko siju imoye ile-aye yi." Nkan ton pe ni prakṣepātmika-śakti niyen. nitorina loje wipe enikan le wa ninu awujo wa, lehin gba die asi pada lo prakṣepāta niyen. O ti ju nu. Afi to ba daju gan, kole gbe pelu wa, maya ma ju sita. Gege na Prahlada Maharaja sowpie awon ona meji wan wayi- inu enikan dun tabi inu enikan o dun- oti pe to tin sele. Konsepe ti ba tun ara imi gba gbogbo e loma tan. Rara. botilejepe eni ara yi, ema ni awon isoro meji wanyi. Enikan ma je ore siyin, elomi a je ota siin. Yoga-samyoga-janma.

lesekese teba lota, ibanuje ma wa. Śokāgninā. Iru ibanuje yi dabi ina ibanuje. Śokāgninā. Śokāgninā sakala-yoniṣu. teyin baro wipe ninu awujo awon eyan nikan lowa - rara ninu gbogbo awon awujo, yoni kankan eyin na ti ri pelu awon eye ologose, ninu awujo awon eye, awon na ja. e ti ri na wantun sere, wan tun ja. Boya eye tabi aja, gbogbo wan lon ja. nkan ton sele iyen, enikan je ore, elomi je ota wansi bere sini ja Sakala-yoniṣu dahyamānaḥ. kosejo pe efe sa kuro ninu awujo eda kan ke salo si ikeje. Kolese se. Ina ija yi ma wa, eto ore ati ota asi wa, nibi, nikankan ko, ninu awon ijoba orun gan Ni ijoba orun, ija wa laarin awon deva ati awon asura awon asura ni itara si awon deva awon deva na ni itara si awon asura Nibikibi. Oba Indra gan, pelu gbogbo owo toni o si lota to po Afe lo si awon ijoba orun lati gbadun sugbon nkankana lo wanbe.