YO/Prabhupada 0364 - To Become Fit for Going Back to Home, Back to Godhead, it is Not so Easy



Lecture on SB 5.5.23 -- Vrndavana, November 10, 1976

Afi t'awa ba ni idari lori awon amuye iranu wanyi bi, t'aimokan ati ikanra, kosi bi inu yin sefe dun. Kolese se. Tato rājas-tamo-bhāvāḥ. Rājas tamo-bhāvāḥ itumo re ni kāma ati lobhā. Tinba l'oju kokoro at'ahun lati ni awon nkan to po si, lati gbadun ara mi si.. oju kokoro niyen. Eyan gbudo ni itelorun, koo ba tie kere.

Āhāra-nidrā-bhaya-maithunaṁ ca sāmānyam etat paśubhir narāṇām. jijeun nitumo Āhāra. Āhāra, nidrā, orun sisun, ati aya jija, ati igbadun. Awon nkan wanyi wulo sugbon awa o gbudo se wan ju, ni iwonba die die lo daa. gege bi eni t'ara reo ba ya, kole jeun bo sefe. Nitoripe aisan wa l'ara re, dokita asi sofun pe " M'omi die tabi glokosi, ma jeun to le, toba fe ki ara re ya." Gege na, awa nkan wanyi si da t'awa ba fe ki ara wa ni pipe. Āhāra-nidrā-bhaya-maithuna. Sugbon agbudo dikun, koye ka je ko posi. Awujo awon eda eyan niyen. Ema je ko posi. Gege bi awon Gosvami ni Vrndavana. Awon eyan yi o wa lati je ki āhāra-nidrā-bhaya-maithuna po si. rara. Wan wa lati le din ku. Nidrāhāra-vihārakādi-vijitau. Nkan ta fe niyen. Vṛndāvana-vasi leleyi, konsepe ka wa ma gbe ni Vṛndāvana lati le je ki āhāra-nidrā-bhaya-maithuna po si. Vṛndāvana-vasa ko niyen. Awon obo yi na wa ni Vrndavana, ati awon aja na, ati awon elede wan gbe ni Vrndavana. sugbon wn o mo bonsele din āhāra-nidrā-bhaya-maithunam ku. E ma ri aawon obo. Awon na wa ni Vrndavana. Sugbon ema ri pe awon obo abo to po gan ton tele awon obo ako vṛndāvana-vāsa ko niyen. Āhāra-nidrā. Itumo re niwipe, awa gbudo ni asa awon brahmana, damo,śamo. nkan ta fe niyen. Asa brahmana niyen. Sugbon awon eyan nisin fe je ki awon nkan yi posi, wan o fe din ku. Igbadun nitumo awujo awon geesi, ero,ero,ero,ero." śamo damo titikṣa nitumo asa brahmana Itumo Titikṣa niwipe laisi nkan mole jiya. Ijiya. Eyan gbudo ko lati jiya. Ijiya. tapasya niyen. Tapasā brahmacaryenā (SB 6.1.13). Tapasya bere lati aimọbinrin Amo ako ati abo tabi igbadun ti mo wa lara. Lati fi ipaari si gbogbo eleyi nitumo Tapasya. Tapasā brahmacaryeṇa (SB 6.1.13). Boseje niyen.

Gege na lati le pada si ijoba orun kon se nkan to rorun. Ko fibe rorun.. Awa gbudo jeki igbadun wa ninu aye yi tan. Oye ko tan pata pata. Anyābhilāṣitā-śūnyam (Brs. 1.1.11). Nkan ta fe niyen, se ikeko. Nitorina, awon egbe imoye Krsna wa, nkan ton wa fun niyen, ikeko nipa śamo damo titikṣa. Nitorina awa fe ri bose le se ikeko fun śamo damo titikṣa.. ti awon omo okurin kan ba wa, wan si fun nise, ise tio le je ko gbadun, nigbo ba ya eyan na asi lo. Itumo re niwipe koi ti daju. O da gan pe wan lo. Ni ede Bengali wan sowipe, dusta gorute sunya goaloa: "teyan ba ni awon maalu ton yaawo, o dara ju ka ma ni awon maalu dipo ta ma ni iru awon maalu bayi." gege na lati fun awon eyan ni ilosiwaju ni'di fun egbe imoye Krsna yi. lati mu awon eyan ton huwa bi eranko sori ipo awon brāhmaṇa. Nitortina la sen fun awon eyan ni okun mimo ni asiko itẹbọmi ikeji, pe " nisin eyan na ti se "śamo damo titikṣa ārjava, eyan na ti ko nkan ti Krsna je, eni toje, iru ibadepo wo loni pelu Krsna, bosele huwa fun itelorun Krsna." Awon amuye brahmana niyen. teyan ba le bosi ipo yi... ipo sattva-guṇa loje.