YO/Prabhupada 0370 - So Far I am Concerned, I Don't Take any Credit



Conversation with Prof. Kotovsky -- June 22, 1971, Moscow

Awon elesin Hindu taye isin le wa, sugbon awa sini awon ohun ogun wa, awon irisi latinu Veda. Koseni toti wa. Sugbon awon alufaa Kristiani.. Awon alufaa Kristiani ni Orile-ede America wan feran mi. Wan sowipe " awon omo-okurin wanyi, awon omo-ilu America, Kristiani lonje, jew lonje. sugbon nisin wanti ni ife Olorun to po ga, awa o si le fun wa nigbala?" Wan ti jewo. Awon baba wan, ebi wan, wan wa s'odo mi. Wansi man dobaale, wansi sowipe, " Swamiji, orire nla loje fun wa pe e wa. Eyin ko awon eyan nipa imoye Olorun." Awon eyan lati aawon ilu imi si feran nkan ti mon se. Ni orile-ede India gan, awon elesin lati orisirisi esin gan wan jewo pe aimoye awon swamiji ton ti lo niwaju mi si awon ilu ajeji, sugbon wan o le so enikan soso di elesin Krsna. Wan nifesi ise yi. sugbon mi o si fe keni kankan ma yin mi logo, sugbon o dami loju pe nitoripe mon gbiyanju lati salaaye imoye Veda gege boseje, lai fi nkankan kun, nitorina lo sen sise. idawo si temi niyen. Geg bi teyin ba ni ogun to da, tesi fun alaisan, o daju na pe eni na ma ni iwosan.