YO/Prabhupada 0405 - The Demons Cannot Understand that the God Can be a Person. That is Demoniac



Lecture on SB 7.7.30-31 -- Mombassa, September 12, 1971

Awon esu wanyi kole ye won pe eyan l'Olorun je. IWa esu niyen. kole.. Nitoripe kole ye won, isoro towa niwipe awon esu ma gbiyanju lati mo nipa Olorun, sugbon asi farare we Olorun.

Dokita. Opolo, itan Dokita. Opolo. Dokita. Opolo fe mo nipa omi Okun sugbon o sin fi kanga re fiwe omi okun, otan. Nigbaton sofun nipa omi okun, o sin fi konga re fiwe. Kosi bosele mo bose tobi to, nitoripe o wa ninu iho kanga kekere. Ore re si sofun, " Oh, moti ri omi okun, tosi tobi gan." sugbon bose tobi to kole ye, O sin beere, " Bawo lose tobi si? Iho kanga yi tobi bayi bayi, se omi okun yi to iye bayi bayi. Sugbon o le gbe iho fun aimoye odun, omi okun si tobi ju lo. Nkan imi niyen. Nitorina awon alainigbagbo, esu, won rowipe Olorun, Krsna bayi lose ri, Bayi ni Krsna se ri, bayi ni Krsna se ri. Bawo lo sen so ? Krsna o lagbara kankan. Won o nigbagbo pe Olorun lagbara. O rowipe oun na dabi Olorun. Olorun nimi. Iwa esu leleyi.