YO/Prabhupada 0406 - Anyone Who Knows the Science of Krishna, He Can be Spiritual Master



Discourse on Lord Caitanya Play Between Srila Prabhupada and Hayagriva -- April 5-6, 1967, San Francisco

Prabhupāda: Ibi t'alakoko ni ile ajosin Vijaya Nṛsiṁha Garh.

Hayagrīva: Vijaya...

Prabhupāda: Vijaya Nṛsiṁha Garh.

Hayagrīva: Sele ko oruko yi funmi toba ya.

Prabhupada: Moti n'pe. V-i-j-a-y N-r-i-s-i-n-g-a G-a-r-h. Ile ajosin Vijaya Nṛsiṁha Garh. O sunmo ibi igbọkọsi Visakhapatnam. Oni ibi igbokosi to tobi gan ni India, Visakhapatnam. Teletele Visakhapatnam ko loruko re je. Lai jina si be ni ile ajosin yi wa lori ipata. O dabi wipe Ile-ajosin yi wa nibe, Caitanya Mahāprabhu de losi be. lehin ile ajosin yi, Osi pada wa si eti omi odo Godavari. Gege bi Omi Ganges se je omi mimo, beena merin na wa to ri bayi. Yamuna, Godavari, Kṛṣṇa, Narmada. Ganga, Yamuna, Godavari, Narmada, ati Kṛṣṇa. Awon odo marun wanyi si je mimo. O si pada s'eti odo Godavari, lati we, osi joko sabe igi lati korin Hare Kṛṣṇa Hare Kṛṣṇa. nigba die o riwipe awon eyan to po rin wa s'odo re, boseye koje niyen... Teletele awon oba at'olori, won man we ninu omi Ganges pelu gbogbo ohun elo ton ni, awon ara ile-ise, awon brahmana ati orisirisi nkan fun saraka. Bayi lon sen man wa we. Beena Oluwa Caitanya si riwipe eyan kan wa pelu awon eyan to po, Wan si sofun nipa Rāmānanda Rāya, olori ijoba Madras. Sārvabhauma Bhaṭṭācārya si sofun eyin fe losi guusu India. Egbodo pade Rāmānanda Rāya. Olufokansi nla loje." Beena nigbato joko s'eti omi odo Kaveri ati nigbati Ramananda Raya sin losi be na pelu awon oni-ise re, Osi yewipe Ramananda Raya loje, sugbon nitoripe sannyasi loje kole ba soro. Sugbon Ramananda Raya toje Olufokansi nla, si ri sannyasi yi to dara, sannyasi towa lasiko odo re, to joko to korin Hare Krsna. Awon sannyasi o kin fibe korin Hare Krsna. Wan korin "Om, om. Sugbon won kin korin Hare Krsna.

Hayagrīva: kinitumo wipe kole ba soro nitoripe o je sannyasi?

Prabhupada: Sannyasin, ihamo to wa nipe eni toje sannyasi ogbodo toro lowo awon onisowo tab ko ri won. Ihamo to wa niyen. Koba je okurin tab'obirin.

Hayagriva: Sugbon mo riwipe olufokansi ni Ramananda Raya je.

Prabhupada: Kosejo pe olufokansi loje, sugbon nita olori ijoba loje. Beena Caitanya Mahāprabhu o lo ba, sugbon o ye wipe " Sannyasi to da leleyi." O si sokale wa lati dobale fun, koto joko si waju re. Wansi pade ara won, Oluwa Caitanya si sofun wipe " Bhattacarya ti soro nipa re simi. Olufokansi nla loje. Beena Moti wa ri e." Lehin na o daun, " Olufokansi? Onisowo nimi, oniselu. Sugbon Bhattacarya si feran me gan to sofun eyan pataki bi eyin ko wa ri mi. Beena teyin se wa, e wa gbami la lowo maya ile aye yi." Wansi fi asiko latipade pelu Ramananda Raya, awon mejeji si pade ni irole, wansi soro nipa eto basele ni ilosiwaju ninu eto emi Oluwa Caitanya si bere lowo re, Ramananda Raya si daaun. Itan to gun gan, nipa awon ibeere ati idaaun.

Hayagrīva: Rāmānanda Rāya.

Prabhupāda: Beeni.

Hayagrīva: se iyen je nkan pataki? Bi ipade won se lo.

Prabhupada: Ipade, ipade, sofe salaaye nipa nkan ton so?

Hayagrīva: Beeni, teba fe ka fi han ninu ere idaray yi. Se fe kin se?

Prabhupada: Nkan tose pataki niwipe o pade Ramananda Raya, o si wa pelu awon eyan to po gan, ibi to da lati fi han niyen. Awon nkan yi to pe. Nisin nipa awon oro ton so, Leenu kan, nkan ton so...

Hayagriva: E salaaye gbogbo e leenu kan.

Prabhupada: Leenu kan. Ninu apa yi Caitanya Mahaprabhu si d'akeko re. Kon se pe o fibe di akeko si, sugbon o si bi Ramananda Raya ni awon ibeere kan. Been nkan tose pataki ninu apa yi niwipe Caitanya Mahaprabhu o tele awon ofin, pe sannyasi nikan loye ko di oluko ninu eto mimo. Enikeni toba nipa sayensi ti Krsna, o le di oluko ninu eto mimo. lati fi han fun ara re, botilejepe o je sannyasi ati brahmana ati wipe Ramananda Raya je sudra ati grhastha, ati olori ile, sugbon osi di oluko si, osi bi Ramananda Raya leere. Ramananda Raya si kanju die pe " Bawo ni mosefe gba ipo oluko si sannyasi yi?" Lehin na Caitanya Mahaprabhu si sofun,, " Rara, rara. Ma kanju>" O si salaaye wipe eyan leje sannyasi tabi olori ile tabi brahmana tabi sudra, kosejo kankan. enikeni toba mo nipa Sayensi Krsna, o le di Oluko. Ibukun re niyen. Nitoripe ninu awujo India, awon rowipe koseni tole di oluko ninu eto mimo afi awon sannyasi ati brahmana. Sugbon Caitanya Mahaprabhu sowipe, " Rara. Enikeni ledi oluko ninu eto mimo, toba si mo nipa sayensi yi." gbogbo oro ipaade yi leenu kan niwipe bawo lasele de ipo to gaju lati niife Olorun. Wansi salaaye nipa ife yi ni pipi ninu eda Radharani. Ninu bhava ati eda Radharani. Ati Ramananda Raya toje Lalita-sakhi ikan ninu awon alabasepo Radharani, awon mejeji si famora wansi bere sini jo pelu idunnu lokan. Ipaare apa i leleyi tefe fihan.. Awon mejeji ton jo.

Hayagrīva: Rāmānanda Rāya.

Prabhupāda: Ati Caitanya Mahāprabhu.

Hayagrīva:O daa be.